Enyinna Nwigwe
Enyinna Nwigwe jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé ati olùgbéré-jáde ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Òun ni ó gbé àwọn aládùn bíi: The Wedding Party, Black November, àti Black Gold jáde.
Enyinna Nwigwe | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Ngor Okpala |
Iléẹ̀kọ́ gíga | University of Calabar |
Iṣẹ́ | Actor, producer |
Ìgbà iṣẹ́ | 2005 - present |
Ìbẹ̀rẹ̀ ayé ati ẹ̀kọ́ rẹ̀
àtúnṣeWọ́n tó Nwigwe ní ìlú Ngor Okpala ní Ìpínlẹ̀ Imo ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. [1] Ó kẹ́kọ̀ọ́ jáde ní ilé-ẹ̀kọ́ fásìtì ti ìlú Calabar ní Ìpínlẹ̀ Delta nínú ìmọ̀ Ìṣúná. [2]
Iṣẹ́ rẹ̀
àtúnṣeNwigwe bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rẹ̀ lásìkò tí ó wà ní ilé-ẹ̀kọ́ Fásitì nígbà tí ó ń ṣiṣẹ́ módẹ́ẹ̀lì pẹ̀lú ilé-iṣẹ́ runway àti print model ṣáájú kí ó tó darapọ̀ mó iṣẹ́ tíátà.[3] Ó gbé eré kan jáde tí ó pè ní Wheel of Change eré tí Jeta Amata darí rẹ̀ ní ọdún 2004. [4]Ní báyìí, Nwigwe ń lọ sí ìlú Los Angeles ati orílẹ̀-èdè Nigeria láti ṣíṣe rẹ̀. [5] Ó ti kópa nínú àwọn eré orísiríṣi ṣáájú kí ó tó kópa nínú eré tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ Black November tí àwọn òṣèré bíi Kim Basinger, Mickey Rourke, Vivica A. Fox, Akon, Wyclef Jean, and Anne Heche ti kópa ní ọdún.[6] Ó kópa bí olú-èdá ìtàn gẹ́gẹ́ bí páítọ̀ nínú eré Hell or High Water, ní ọdún 2015. Lẹ́yìn eré yí ni ó pinu láti máa kòpa nínú eré tí ó bá ti níṣe pẹ̀lú ìṣẹ̀lẹ̀ àwùjọ.[7][8] Ní ọdún 2017, News of Africa pèé ní Ẹni àkọ́kọ́ nínú àwọn méjìlá tí ojú wọn fani-mọ́ra jùlọ ní Nollywood, lọ́dún náà. [9]
Àwọn eré rẹ̀
àtúnṣeỌdún | Àkọ́lé eré | Ioa tí ó kó | Àríwísí |
---|---|---|---|
2005 | Wheel of Change | Tony | |
Last Game | Gubabi | ||
2006 | Games Men Play | Attorney | |
The Amazing Grace | Etukudo, Associate Producer | ||
2011 | Black Gold | Tamuno, Co-Producer | |
2012 | Turning Point | Steve | |
Black November | Tamuno Alaibe, Associate Producer | ||
2015 | Silver Rain | Bruce | |
Love Struck | Actor | TV Movie | |
2016 | Put a Ring on It | Robert | |
Hell or High Water | Actor | Short Film | |
When Love Happens Again | Enyinna | ||
Dinner | Adetunde George Jnr. | ||
The Wedding Party | Nonso Onwuka | ||
2017 | Hire A Man | Jeff | |
Red Code | Charles | ||
Atlas | Osas | ||
The Wedding Party 2 | Nonso | ||
2019 | Living in Bondage: Breaking Free | Obinna Omego | |
2019 | Cold Feet | Tare | |
2020 | Dear Affy | Micheal |
Àwọn eré orì amóhù-máwòrán
àtúnṣeỌdún | Àkọ́lé | Ipa tí ó kó | Àríwísí |
---|---|---|---|
2008 | Mary Slessor | Prince, Producer |
Àwọn amì-ẹ̀yẹ ati ìfisọrí rẹ̀
àtúnṣeWọ́n yan Nwigwe amì-ẹ̀yẹ ti Nollywood and African Film Critics Award, ní ọdún 2015, ati òṣèré amúgbá-lẹ́gbẹ̀ẹ́ tí ó peregedé jùlọ níbi ayẹyẹ African Oscars nínú eré Black November.[11] Ní ọdún 2016, wọ́n tún yàn án fún amúgbálẹ́gbẹ̀ẹ́ tí ó peregedé jùlọ nínú eré Gẹ̀ẹ́sì níbi amì-ẹ̀yẹ City People Entertainment Awards.[12]
Àwọn Ìtàkùn ìjásóde
àtúnṣeÀwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "I Don’t Want To Be Another Actor – Enyinna Nwigwe" (in en-US). Top Celebrities Magazine. 2015-04-01. Archived from the original on 2017-08-01. https://web.archive.org/web/20170801154923/https://www.topcelebritiesng.com/i-dont-want-to-be-another-actor-enyinna-nwigwe/.
- ↑ "Biography/Profile/History Of Nollywood actor Enyinna Nwigwe – Daily Media Nigeria". dailymedia.com.ng (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2017-07-04.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ "Enyinna Nwigwe – Runway model to award-winning actor" (in en-US). Archived from the original on 2017-06-30. https://web.archive.org/web/20170630031529/http://guardian.ng/life/spotlight/enyinna-nwigwe-runway-model-to-award-winning-actor/.
- ↑ AsuquoE (2014-12-23). "Meet Enyinna Nwigwe - The talented and good-looking Nigerian born Nollywood Actor and Producer on an impressive climb to stardom". TalkMedia Africa. Retrieved 2017-07-05.
- ↑ Izuzu, Chidumga. "Enyinna Nwigwe: Here"s everything you need to know about actor"s "unusual" character in "Suru L" ere"" (in en-US). Archived from the original on 2017-08-01. https://web.archive.org/web/20170801164447/http://www.pulse.ng/movies/enyinna-nwigwe-heres-everything-you-need-to-know-about-actors-unusual-character-in-suru-l-ere-id4608003.html.
- ↑ Offiong, Adie Vanessa (March 4, 2017). "I want to win an Oscar –Enyinna Nwigwe". Daily Trust. Archived from the original on August 1, 2017. Retrieved July 4, 2017.
- ↑ "Enyinna Nwigwe talks shooting gay scene with actor Daniel K Daniel - Nigerian Entertainment Today - Nigeria's Top Website for News, Gossip, Comedy, Videos, Blogs, Events, Weddings, Nollywood, Celebs, Scoop and Games" (in en-GB). Nigerian Entertainment Today - Nigeria's Top Website for News, Gossip, Comedy, Videos, Blogs, Events, Weddings, Nollywood, Celebs, Scoop and Games. 2016-06-13. http://thenet.ng/2016/06/enyinna-nwigwe-talks-shooting-gay-scene-with-actor-daniel-k-daniel/.
- ↑ "Enyinna Nwigwe, Daniel K. Daniel, and others give rousing performances in gay-themed movie, Hell or High Water » YNaija" (in en-GB). YNaija. 2017-03-31. https://ynaija.com/enyinna-nwigwe-daniel-k-daniel-others-give-rousing-performance-gay-themed-movie-hell-high-water/.
- ↑ "Meet The 12 Sexiest Nollywood Actors in 2017 (Photos)" (in en-US). News of Africa - Online Entertainment - Gossip - Celebrity Newspaper - Breaking News. 2017-03-22. Archived from the original on 2018-02-17. https://web.archive.org/web/20180217041852/http://newsofafrica.org/205746.html.
- ↑ "Enyinna Nwigwe". IMDb. Retrieved 2017-07-04.
- ↑ Editor, The (2015-07-02). "Oprah Winfrey, Vivica Fox, RMD, AY & Others make Nollywood & African Film Critics’ Awards (NAFCA) Nominees List". Nollywood Observer. Retrieved 2017-07-04.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ Izuzu, Chidumga. "City People Entertainment Awards 2016: "Suru L"ere," "Tinsel," Adeniyi Johnson, Mide Martins among nominees" (in en-US). http://www.pulse.ng/movies/city-people-entertainment-awards-2016-suru-lere-tinsel-adeniyi-johnson-mide-martins-among-nominees-id5249079.html.