Black November
Black November: Struggle for the Niger Delta jẹ́ fíìmù Nàìjíríà tó tan mọ́ ti ilẹ̀ Hakeem Kae-Kazim, Mickey Rourke, Kim Basinger, Fred Amata, Sarah Wayne Callies, Nse Ikpe-Etim, OC Ukeje, Vivica Fox, Anne Heche, Persia White, Akon, Wyclef Jean àti Mbong Amata ló kópa nínú fíìmù náà. [2][3] Jeta Amata ni olùdarí fíìmù yìí, ìtàn náà sì dá lórí ìtàn agbègbè Niger Delta àti akitiyan wọ́n láti ṣe lòdì sí ìjọba tó ń ba ìlú náà jẹ́, àti láti ṣe ìràpadà ìlú wọn tó ti ń lọ sí oko ìparun látàrí epo rọ̀bì tí wọ́n ń jí bù. [4]
Black November | |
---|---|
[[File:|200px|alt=]] Theatrical release poster | |
Adarí | Jeta Amata |
Olùgbékalẹ̀ | Bernard Alexander Jeta Amata Ori Ayonmike Marc Byers Wilson Ebiye Hakeem Kae-Kazim Dede Mabiaku |
Òǹkọ̀wé | Jeta Amata |
Asọ̀tàn | Kara Noble |
Àwọn òṣèré | |
Orin | Joel Goffin |
Ìyàwòrán sinimá | James Michael Costello Tommy Maddox-Upshaw |
Olóòtú | Debbie Berman Lindsay Kent Adam Varney |
Ilé-iṣẹ́ fíìmù | Wells & Jeta Entertainment |
Olùpín | eOne Entertainment (United States) |
Déètì àgbéjáde |
|
Àkókò | 95 minutes |
Orílẹ̀-èdè | Nigeria United States |
Èdè | English |
Ìnáwó | ₦2 billion (shared with Black Gold)[1] (US$12.5 million) |
Àkọlé yìí, ìyẹn Black November wáyé látàrí ìṣẹ̀lẹ̀ tó ṣẹlẹ̀ ní oṣù náà, nígbà tí wọ́n pa ajàfẹ́tọ̀ọ́ ọmọnìyàn, ìyẹn Ken Saro-Wiwa ní ọdún 1995 [5] Fíìmù yìí fẹ́ fara jọ fíìmù ọdún 2011 kan, tí àkọlé rẹ̀ ń jẹ́ Black Gold.Wọ́n tún àwọn ìran kan yà, wọ́n sì ṣàfikún sí fíìmù náà. .[6] Bernard Alexander Ori Ayonmike, Marc Byers, Wilson Ebiye, Hakeem Kae-Kazim àti Dede Mabiaku ló ṣàgbéjáde fíìmù Black November. Owó tí wọ́n fi àgbéjáde fíìmù yìí wọ US$22 million,[7] èyí tí ó ti ọwọ́ elépo rọ̀bì kan wá. [7]
Àwọn akópa
àtúnṣe- Mbong Amata bíi Ebiere Perema
- Hakeem Kae-Kazim] bíi Dede
- Enyinna Nwigwe bíi Tamuno Alaibe
- Mickey Rourke bíi Tom Hudson
- Sarah Wayne Callies bíi Kate Summers
- Kim Basinger bíi Kristy
- OC Ukeje bíi Peter Gadibia
- Vivica Fox bíi Angela
- Persia White bíi Tracey
- Fred Amata bíi Gideon white
- Wyclef Jean bíi Timi Gabriel
- Akon as Opuwei
- Nse Ikpe-Etim bíi Ebiere's Attorney
- Barbara Soky bíi Franca
- Dede Mabiaku bíi Captain Hassan
- Zack Amata bíi Chief Kuku
- Isaac Yongo bíi Chief Gadibia
- William Goldman bíi Rick Peterson
- Anne Heche bíi Barbra
- Lanny Joon bíi Agent Cole
- Stefanie Kleine bíi Madeline
- Emmanuel Okhakhu bíi Chief Okon
- Ivar Brogger bíi Bellamy
- Nathin Butler bíi Jack
- Jane Unogwu bíi Hosanna
- Razaaq Adoti bíi Timi
- Cindy Vela bíi Dj star original
Ìgbéjáde fún àwùjọ
àtúnṣeÌpolówó fíìmù Black November jáde sí àwùjọ lórí YouTube ní ọjọ́ kẹrin oṣù kẹrin, ọdún 2012.[8] Ìṣàfihàn àkọ́kọ́ ti fíìmù náà wáyé ní [[John F. Kennedy Center for the Performing Arts ní ọjọ́ kẹjọ oṣù karùn-ún, ọdún 2012.[7][9] Lára àwọn ènìyàn pàtàkì tó farahàn níbi ayẹyẹ náà ni Agbani Darego, Dan Glickman, Gabon Ambassador Michael Moussa, aṣojú ìlú US ìgbà kan, ìyẹn Shirley Barnes, Robin Sanders àti Isyaku Ibrahim.[10] Wọ́n tún ṣàfihàn rẹ̀ ní ọjọ́ kẹrìndínlọ́gbọ̀n oṣù kẹsàn-án ọdún 2012, lásìkò United Nations General Assembly ní New York City, èyí tí àwọn akópa fíìmù náà farahàn nínú. Àwọn gbajúmọ̀ òṣèré mìíràn náà farahàn níbi ayẹyẹ náà. [11] It went on general release in Nigeria on 21 December 2012.[12][13] Ìpolówó ti US fún fíìmù náà wáyé ní ọjọ́ karùndínlógún oṣù kẹsàn-án ọdún 2014,[14] wọ́n sì gbé fíìmù náà jáde fún wíwò àwọn ènìyàn ní àwùjọ ní United States láti ọwọ́ eOne Entertainment ní ọjọ́ kẹsàn-án oṣù kìíní ọdún 2015.[15][16] Wọ́n tún gbé fíìmù náà jáde ní orí DVD, iTunes, Amazon, àti àwọn ìkànni mìíràn ní ọdún 2015.[16]
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Black November (2012) - Box Office/Business". IMDB. Archived from the original on 14 November 2021. Retrieved 30 June 2014. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Wyclef Jean & Akon Starring in Black November". Archived from the original on 5 December 2020. Retrieved 30 June 2014. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Wyclef Jean and Akon will star in Jeta Amata's Nollywood production, Black November". All African Cinema. 4 September 2012. Archived from the original on 4 March 2016. Retrieved 30 June 2014. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Kogbara, Donu; Otas, Belinda (29 August 2012). "Black November: Niger Delta film spills powerful story". The Africa Report. Archived from the original on 14 July 2014. Retrieved 30 June 2014. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Seun (5 April 2013). "What Jeta Amata Told Cnn About his new Movie Black November". BON. Best of Nollywood. Archived from the original on 23 September 2015. Retrieved 2 August 2014. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Hoad, Phil (1 February 2012). "Is Jeta Amata Nollywood's gift to Hollywood?". The Guardian. Archived from the original on 23 September 2015. Retrieved 30 June 2014. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ 7.0 7.1 7.2 Kogbara, Donu; Otas, Belinda (29 August 2012). "Black November: Niger Delta film spills powerful story". The Africa Report. Archived from the original on 14 July 2014. Retrieved 31 July 2014. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Jeta Amata Releases Black November Trailer". Nollywood Mindspace. 5 April 2012. Archived from the original on 8 August 2014. Retrieved 2 August 2014. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedAll African cinemas
- ↑ "Exclusive Pictures From Jeta Amata's 'Black November' Movie Premiere". Nigeria Films. 13 May 2012. Archived from the original on 2015-04-06. Retrieved 2 August 2014. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedautogenerated3
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedautogenerated4
- ↑ "Jeta Amata set to release Black November: December 2012!". 9jabooksandmovies. 17 September 2012. Archived from the original on 14 August 2014. Retrieved 2 August 2014. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Black November (Feat. Akon, Wyclef & More) (Movie Trailer) [eOne Films Submitted]". Archived from the original on 17 November 2023. Retrieved 14 March 2015. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Gallagher, Brian (9 January 2015). "'Black November' Interview with Sarah Wayne Callies". Movie Web. Archived from the original on 2 April 2015. Retrieved 14 March 2015. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ 16.0 16.1 "Hollywood Stars Commend Nigerian Film-Maker Jeta Amata on 'Black November', Currently Showing on VOD". bellanaija.com. 20 January 2015. Archived from the original on 2 April 2015. Retrieved 14 March 2015. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)