Enyinnaya Abaribe

Olóṣèlú Nàìjíríà

Enyinnaya Abaribe (bíi ní Ọjọ́ kẹta Oṣù kẹta Ọdún 1955) jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí wọ́n dìbò yàn wọlé gẹ́gẹ́ bí aṣojú Gúúsù Abia, ìpínlẹ̀ Abia ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà. Ó jẹ́ aṣojú ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin láti ọdún 2011 sí 2015 lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú People's Democratic Party.[1]

Enyinnaya Harcourt Abaribe
Aṣojú àríwá Abia ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
Ọjọ́ ọ̀kàndínlọ́gbọ̀ Oṣù karún Ọdún 2007
AsíwájúAdolphus Wabara
Igbá kejì Gómìnà Abia
In office
Ọjọ́ Ọ̀kàndínlọ́gbọ̀ Oṣù karún Ọdún 1999 – Ọjọ́ keje Oṣù kẹta Ọdún 2003
GómìnàOrji Uzor Kalu
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí1 Oṣù Kẹta 1955 (1955-03-01) (ọmọ ọdún 69)
Aba, ìpínlẹ̀ Abia , Nàìjíríà
Ọmọorílẹ̀-èdèọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà
Ẹgbẹ́ olóṣèlúPDP ( ANPP tẹ́lẹ̀)
(Àwọn) olólùfẹ́Florence Nwamaka (nee Morris)

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. ORJI UZOR KALU (10 April 2011). "Orji Kalu Fails; Abaribe, Chukwumerije, Nwaogu Reelected Senators". Online Nigeria. Archived from the original on 2011-07-28. Retrieved 2011-04-20.