Esther Ijewere-Kalejaiye
Esther Ijewere-Kalejaiye jẹ́ olùkọ̀wé obìnrin ọmọ Nàíjír̀a, alágbàwí, onígbèjà àwọn obìrin àti àwọn ̣ọmọdébìrin àti akọrọ̀yìn ní Ilé-ìròhìn The Guardian.
Esther Ijewere- Kalejaiye | |
---|---|
Ibùgbé | Ìlú Èkó, Nàìjíríà |
Orílẹ̀-èdè | Ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà |
Iṣẹ́ | Akọ̀wé àti Ajìjàgbra |
Gbajúmọ̀ fún | Ìwé kíkọ̀ àti Walk Against Rape |
Title | Aláṣẹ àti Olùdarí |
Ìgbésíayé
àtúnṣeÓ kàwégboyè nínú ìmọ̀ Sociology láti Olabisi Onabanjo University, Àgó-Íwòyè, Ogun State, Nàìj́írìa,[1] Ijewere-Kalejaiye ni olùdásílẹ̀ Rubies Ink Initiative fún àwọn obìrin àti ọmọdé, Ilé-iṣẹ́ tí ńṣe agbọ̀rọ̀dùn fún àwọn obìnrin àti ọmọdébìrin pẹ̀lú Walk Against Rape, Women of Rubies, Project Capable, Rubies Ink Media àti College Acquaintance Rape Education Workshop.[2] Ní ọdún 2013, Ìjàgbara rẹ̀ láti lè dojú ìjà kọ ìfi ípa bá obìnrin lò mu u kọ ìwé Breaking the Silence, ìwé tí on filọ̀ nípa ìfi ípa bá obìnrin lò àti okùnfà rẹ̀.[3] Àwọn ojúṣe rẹ̀ sí àwùjọ Nàìj́írìa ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ ilé-ẹ̀kọ́ àti Ilé-iṣẹ́ ̀Ijọba ní wọ́n tí ṣe ìránt́i rẹ.[4] Ní ọjọ́ kẹsan oṣù keje ọdún 2016, wọ́n fún ní ẹ̀bùn “Young Person of the Year Award” ní Miss Tourism Nigeria beauty pageant ti ọdún 2016 .[5] Ó tún gba ẹ̀bùn Wise Women Awards ti "Christian Woman in Media Award" tí ó gba nínú osù kẹfà nínú odún 2016.[6] Ijewere-Kalejaiye tí ṣe ìgbéyàwó pẹ̀lu ọmọ méjì.[1]
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ 1.0 1.1 Joseph, Tinuola (13 December 2013). "‘Rape victims now come out and talk’ – Esther Ijewere-Kalejaiye unveils Breaking the Silence". Ecomium Magazine. http://encomium.ng/rape-victims-now-come-out-and-talk-esther-ijewere-kalejaiye-unveils-breaking-the-silence/. Retrieved 18 July 2016.
- ↑ "CEO of Rubies Ink, Ijewere-Kalejaiye, wins ‘Young Person of the Year Award’". The Eagle (News Agency of Nigeria). 11 July 2016. http://theeagleonline.com.ng/ceo-of-rubies-ink-ijewere-kalejaiye-wins-young-person-of-the-year-award/. Retrieved 18 July 2016.
- ↑ Ajose, Kehinde (4 April 2015). "Speaking up against rape helps the victims get justice — Esther Ijewere Kalejaiye". Vanguard News. http://www.vanguardngr.com/2015/04/speaking-up-against-rape-helps-the-victims-get-justice-esther-ijewere-kalejaiye/. Retrieved 18 July 2016.
- ↑ Kolapo Olapoju (13 February 2015). "Rubies Ink partners with LASG to organize C.A.R.E workshop". YNaija. http://ynaija.com/rubies-ink-partners-with-lasg-to-organize-c-a-r-e-workshop/. Retrieved 18 July 2016.
- ↑ "CEO of Rubies Ink, Esther Ijewere-Kalejaiye :Wins “young person of the year award”". The Guardian News. 16 July 2016. http://m.guardian.ng/guardian-woman/ceo-of-rubies-ink-esther-ijewere-kalejaiye-wins-young-person-of-the-year-award/. Retrieved 18 July 2016.
- ↑ Yusuf Adeoye (27 June 2016).