Bàbá
(Àtúnjúwe láti Father)
Bàbá ni ọbí to je ọkùnrin eyan kan. Opolopo awon ẹranko ati eniyan ni won ni ìyá ati baba to bi won.[1][2]
Ni awon àṣà miran won pe baba ni okunrin to dagba tabi to nipo ju onitoun lo. Bakanna awon elesin Kristiani n pe ọlọ́run ni baba: "Baba wa ti n be ni orun"[3]
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
àtúnṣe- ↑ "Definition of father". www.dictionary.com. 2019-05-09. Retrieved 2023-06-12.
- ↑ "Who is a father? Here are 10 definitions we think sum him up best". The Indian Express. 2017-10-23. Retrieved 2023-06-12.
- ↑ "Báwo Ló Ṣe Yẹ Ká Máa Gbàdúrà sí Ọlọ́run?". JW.ORG. Retrieved 2023-06-12.