Festus Olúwọlé Ṣẹ́gun jẹ́ ọmọ bíbí ìlú Ijebu Ode, tí wọ́n bí ní (20 March 1915). Ni ó jẹ́ Bíṣọ́ọ́bù Anglican .[1]

Ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ (Our Saviour's Primary School) ní ìlú Ìjẹ̀bú-Òde, ó tún lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ girama (St. Andrew's College) ní ìlú Ọyọ́ àti Fourah Bay College, Sierra Leone.

Wọ́n yàán gẹ́gẹ́ bí Díákónì ìjọ Anglica ní ọdún 1951, bákan náà ni wọ́n yàán gẹ́gẹ́ bí Olùṣọ́t ní ọdún 1952.[2] Ó di ipò yí mú ní ilé ìjọsìn ti Ebute Metta, Aroloya àti ilé ìjọsìn ti Yábàá 1956-1960. Ó kẹ́kọ̀ọ́ nípa Union Theological Seminary in New York City, ṣájú kí ótó di Olùkọ́ ní St Augustine's College, Canterbury. Nígbà tí ó padà sí ìlú Èkó, wọ́n yàán gẹ́gẹ́ bí Ọ̀gá àgbà fún Cathedral Church of Christ, Lagos, ó di ipò yí mú títí di ọdún 1970 nìgbà tí ó dépòBishop ní apá Gúsù Nàìjíríà.[3] Wọ́n gbe padà sí ìlú Èkó ní ọdún 1975.

Àwọn àkọsílẹ̀ àtúnṣe

  1. Empty citation (help) 
  2. Crockford's Clerical Directory 1975-76 London: Oxford University Press, 1976 ISBN 0-19-200008-X
  3. "Osun Defender". Archived from the original on 2015-06-01. Retrieved 2019-05-12.