Olufunmilayo Aduni Olayinka, orúko abiso rè ni Famuagun (tí a bí ní ọjọ́ ogún oṣù kẹfà ọdun 1960 tí o sì di ologbe ní ọjọ́ kẹfà oṣù kẹrin 2013) jé akawo ilé ifowopamo àti olósèlú nígbà ayé rè. O jé okàn lara awon ígbákejì Gomina ìpínlè Ekiti teleri.[1][2]

Olufunmilayo Aduni Olayinka
Ìgbàkejì Gómìnà ìpínlè Ekiti tẹ́lẹ̀ rí
In office
15 October 2010 – 6 April 2013 (died in office)
GómìnàKayode Fayemi
AsíwájúDr. Sikiru Tae Lawal
Arọ́pòProfessor Modupe Adelabu
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí(1960-06-20)20 Oṣù Kẹfà 1960
Ado-Ekiti, Nigeria
Aláìsí6 April 2013(2013-04-06) (ọmọ ọdún 52)
Lagos, Nigeria
Resting placeAdo-Ekiti
Ọmọorílẹ̀-èdèNigerian
Ẹgbẹ́ olóṣèlúAction Congress of Nigeria
Alma materCentral State University, Wilberforce, Ohio, United States

Àárò ayé àti èkó rè

àtúnṣe

A bí Olayinka ní ìlú Ado-Ekiti, ìpinlè Ekiti. O kàwé ní ilé-ìwé Holy Trinity Grammar School ní ìlú Ibadan, kí o to di wipe o lo sí Oliver Baptist High School, Ìpínlè Oyo, Naijiria. O gba àmì-èye Bachelor of business Administration marketing àti Àmì-èye master degree nínú public administration ní ilé-ìwé Central State University, ìpínlè Ohio, orílè-èdè Amerika.

Isé rè

àtúnṣe

Olayinka bèrè isé rè pèlú First Bank of Nigeria plc ní odun 1986. O pada sísé ní ilé ifowopamosi access bank àti United bank of Africa náà.

Ni osu kejo odun 2002, o di olori eka cooperate affairs ti United Bank of Africa(UBA), o tún pada di ígbákejì àjo awon Cooperate Managers fún àwon Ile ifowopamo ni odun 2002 si odun 2004.[3] Ko to dipe ayan gege bi igbakeji Gomina ìpinlè Ekiti, o jé olori co-operate affairs ti ilé ifowopamosi Ecobank Transatlantic Inc.

Iyan sípò rè

àtúnṣe

Léyìn idibo odun 2007, a yan Segun Oni, omo egbe oselu People's Democratic Party(PDP) sípò. Èyí mú kí Olayemi àti Kayode Feyemi gbé oro náà sílé ejo pé awon ni o to sipo náà, léyìn odun meta abo, ayo Segun Oni nipo, ásì gbé Dr. Kayode Feyemi ti Action Congress of Nigeria(ACN) sípò Gomina, èyi mu ki ayàn Olayemi gegebi ígbákejì[4] Oun ni obinrin kejì nínú ìtàn láti dé ipò igbakeji Gomina ìpinlè Ekiti

Ikú rè

àtúnṣe

Olayinka fi ayé sílè ní 6 April 2013, okunfa ikú rè ni aàrùn kogbogun Cancer, a sin sí ìpinlè Ekiti[5] o fi oko rè àti àwon omo méjì saye.

Àwon Ìtókasí

àtúnṣe
  1. Ariyibi, Gbenga (26 April 2013). "Body of Funmilayo Olayinka, Ekiti Deputy Gov laid to rest". Vanguard. http://www.vanguardngr.com/2013/04/body-of-funmilayo-olayinka-ekiti-deputy-gov-laid-to-rest/. Retrieved 1 July 2013. 
  2. "Deputy Governor of Ekiti State Mrs Funmilayo Olayinka Is dead". naij.com. 6 April 2013. http://news.naij.com/30149.html. Retrieved 1 July 2013. 
  3. "Biography of Mrs Funmi Olayinka – Ekiti State Website". Ekiti State Website – Official Website of the Government of Ekiti State. 2019-09-15. Retrieved 2022-05-30. 
  4. "The Sun News On-line -". sunnewsonline.com. 2010-10-21. Archived from the original on 2010-10-21. Retrieved 2022-05-30.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  5. </nowiki>"Body of Funmilayo Olayinka, Ekiti Deputy Gov laid to rest". Vanguard News. 2013-04-26. Retrieved 2022-05-30. <nowiki>