Gògóńgò
Gògóńgò ni ó jẹ́ ọ̀kan lára ẹ́yà ara ìfọ̀ tí ó wà ní iwájú ọrùn gbogbo ẹranko elégungun.
Throat | |
---|---|
The human throat. | |
X-ray showing the throat, seen as a dark band to the front of the spine. | |
Details | |
Identifiers | |
Latin | gula jugulum |
FMA | 228738 |
Anatomical terminology |
Iṣẹ́ rẹ̀
àtúnṣeGògóńgò ni ó ń ṣàkóso bí ohun jíjẹ àti mímu kò ṣe ní gba òdì nípa ṣíṣètò ìyàtọ̀ láàrin ònfà ọ̀fun, ohùn àti tááná tí ó gbé èémí jáde nígbà tí a bá ń jẹun lọ́wọ́. Gògóńgò tí a ń sọ̀rọ̀ rẹ̀ yí náà ni ó tún gbé ọ̀pá ẹ̀jẹ̀ (blood vessel) oríṣríṣi. Gògóńgò ẹranko elégungun ní oríṣríṣi eegun méjì tí a mọ̀ sí (egungun hyoid) àti (clavicle).[1] Ẹ̀wẹ̀, gògóńgò tún ń ṣíṣẹ́ pẹ̀lú ẹnu, etí,imú àti púpọ̀ nínú àwọn ẹ̀yà ara gbogbo.[2]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "throat" at Dorland's Medical Dictionary
- ↑ "Throat anatomy and physiology". Children's Hospital of Philadelphia. Retrieved 7 August15. Check date values in:
|access-date=
(help)