Gwagwalada jẹ́ ọ̀kan lára àwọn Íjọba Ìbílẹ̀Federal Capital Territory, orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.

Gwagwalada
Country Nigeria
TerritoryFederal Capital Territory
Government
 • Executive chairmanAlhaji Abubakar Jibrin Giri
Time zoneUTC+1 (WAT)
6-digit postal code
902101
Area code(s)NG.AB.GW
Websitehttp://www.fctacss.org.ng/index.php/area-councils/gwagwalada-area-council

Gwagwalada ní ilẹ̀ tí ó tó 1,043 km2 àti olùgbé 157,770 ní ìgbà ìkànìyàn ti ọdún 2006. Kí wọ́n wọ́n tó dá Gwagwalada kalẹ̀, ó wà lábẹ́ agbègbè Kwali ti Abuja tẹ́lẹ̀.

Post office ní Gwagwalada

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe