Hakeem Effects (tí orúkọ àbísọ rẹ̀ jẹ́ Hakeem Onilogbo Ajibola), jẹ́ amójú ẹni gúnrégé fún àwọn eléré Nollywood, tí ó sojúdé àwọn èyí tó dá yàtọ̀ níbi ka fojú ẹni dárà[1] [2][3]. Ó jẹ́ olùdásílẹ̀ àti olùdarí "Tricks International"; tí ó jẹ́ ilé-iṣẹ́ tó ń fojú ẹni dárà, tí ó sì ti ṣiṣẹ́ pẹ̀lú ọ̀pọ̀lọpọ̀ eléré fíìmù àgbéléwò Nollywood [4]. A mọ̀ ọ́n fún àwọn iṣẹ́ tó ti ṣe nínú àwọn fíìmú bí i King of Boys àti Omo Ghetto: The Saga, àti àwọn fọ́nrán orin lóríṣiríṣi[5]. Ní ọdún, ó gba àmì-ẹ̀yẹ fún "Best Make-up", ní Africa Magic Viewers Choice Award fún Oloibiri[6][7][8] àti Africa’s Best Makeup Artist ní ayẹyẹ ọdún 2016 àti ti 2017 èyí tí Africa Movie Academy Awards ṣe[9][10].

Hakeem Effects
Ọjọ́ìbíIbadan, Nigeria
Orílẹ̀-èdèNigerian
Ọmọ orílẹ̀-èdèNigerian
Iṣẹ́make-up artist
Olólùfẹ́
Oluwaseun Onilogbo (m. 2008)

Àtòjọ àwọn fíìmù rẹ̀

àtúnṣe

Fíìmù àgbéléwò àti ètò orí ẹ̀rọ-amóhùnmáwòrán

àtúnṣe
Ọdún Iṣẹ́ Ojúṣe Ọ̀rọ̀
2012 Okafor's Law special makeup effects
2017 House on the Hill special makeup effects
2018 The Delivery Boy special effects coordinator
King of Boys special effects supervisor
2019 Blameless make-up, special effects
2020 The Milkmaid make-up
Omo Ghetto: The Saga make-up, special effects
2021 Lugard special effects
2021 Plus Hubby Special effects
2021 King of Boys: The Return of the King special effects coordinator
2021 Online Special effects
2021 Manifestation Special effects

Awards and nominations

àtúnṣe
Ọdún Ayẹyẹ Ẹ̀bùn Iṣé Èsì Ìtọ́ka
2017 2017 Africa Magic Viewers Choice Awards Best Make-up Artist Oloibiri Gbàá [6]
2018 2018 Africa Magic Viewers' Choice Awards|2018 Africa Magic Viewers Choice Awards Tatu Gbàá [11]
Disguise Wọ́n pèé
2023 2023 Africa Magic Viewers' Choice Awards Anikulapo   Iṣẹ́ ń lọ lórí ẹ̀ [12]
Shanty Town   Iṣẹ́ ń lọ lórí ẹ̀
Battle on Buka Street   Iṣẹ́ ń lọ lórí ẹ̀

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "My husband and I never dated–LOLA MAJA OKOJEVOH". The NATION. 19 April 2015. Retrieved 25 June 2016. 
  2. "Hunger motivated my interest in special effects make-up — Hakeem Onilogbo". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-09-09. Retrieved 2022-07-22. 
  3. Alawode, Abisola (2017-01-12). "Can you tell if this gory video is real or its just makeup?". Legit.ng - Nigeria news. (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2022-07-22. Retrieved 2022-07-22. 
  4. "'I don turn black pesin to oyibo before'". BBC News Pidgin. 2018-11-12. Retrieved 2022-07-22. 
  5. "Nollywood award winning Makeup Artist Hakeem Onilogbo – he makes Buhari look-alike turned a black person white for the movies - CyberTranic". cybertranic.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-11-16. Retrieved 2022-07-22. 
  6. 6.0 6.1 "'76' is Best movie at AMVCA 2017". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2017-03-04. Retrieved 2022-07-22. 
  7. BusinessDay (2017-03-05). "“76” biggest winner at AMVCA 2017". Businessday NG (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-07-22. 
  8. Inyang, Ifreke (2017-03-05). "'76' wins five awards at AMVCA 2017 [See full list of winners]". Daily Post Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-07-22. 
  9. enkay. "Hakeem Onilogbo Ajibola wins in Best Makeup artist category". Ivory NG (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-07-22. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  10. PositiveNaija (2019-10-31). "Winners Of 2019 Africa Movie Academy Awards (AMAA)". PositiveNaija (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-07-22. 
  11. "AMVCA 2018: Full list of winners". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-09-02. Retrieved 2022-07-22. 
  12. "Full List: Here are all our AMVCA 9 Nominees". AMVCA - Full List: Here are all our AMVCA 9 Nominees (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-04-23. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]