Omo Ghetto: The Saga
Omo Ghetto: The Saga | |
---|---|
Fáìlì:Omo Ghetto The Saga Poster.jpg Promotional poster | |
Adarí | JJC Skillz Funke Akindele |
Olùgbékalẹ̀ | Funke Akindele Wendy Uwadiae Imasuen |
Àwọn òṣèré | Funke Akindele Chioma Akpotha Nancy Isime Eniola Badmus Bimbo Thomas Mercy Aigbe Deyemi Okanlawon Timini Egbuson Alex Ekubo |
Ìyàwòrán sinimá | John Dems |
Olóòtú | JJC Skillz Valentine Chukwuma Adeyemi Adeshomade |
Ilé-iṣẹ́ fíìmù | Scene One Productions |
Olùpín | FilmOne Distribution |
Déètì àgbéjáde |
|
Àkókò | 110 minutes |
Orílẹ̀-èdè | Nigeria |
Èdè | English, Yoruba, Igbo, Hausa, Nigerian Pidgin |
Owó àrígbàwọlé | ₦636.1 million[1] |
Omo Ghetto: The Saga tí a tún mọ̀ sí Omo Ghetto 2[2] jẹ́ fíìmù àwàdà oníjàgídíjàgan tí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó jáde ní ọdún 2020, tí Funke Akindele àti JJC Skillz ṣe adarí rẹ̀[3]. Àwọn gbajúgbajà fíìmù náà ni Funke Akindele, Chioma Akpota, Nancy Isime, Eniola Badmus, Bimbo Thomas, Deyemi Okanlawon àti Mercy Aigbe. Èyí ni fíìmù apá kejì ti Omo Ghetto, àti pé ó jẹ́ ìtẹ̀síwájú fíìmùOmo Ghetto tó jáde ní ọdún 2010[4]. Ní ọjọ́ 26 oṣù January, ọdún 2021, nígbà tí fíìmù náà kọ́kọ́ jáde wọ́n rí tó ₦468 million, ní èyí tó ju ti The Wedding Party lọ. Ó sì mu kó jẹ́ fíìmù àgbéléwò tó ní èrè tó pọ̀l jù lọ ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà[5][6].
Àwọn akópa
àtúnṣe- Funke Akindele gẹ́gẹ́ bí i Lefty(Shalewa) àti Ayomide
- Bimbo Thomas gẹ́gẹ́ bí i Nikky
- Eniola Badmus gẹ́gẹ́ bí i Busty
- Chioma Chukwuka gẹ́gẹ́ bí i Chummy Choko
- Deyemi Okanlawon gẹ́gẹ́ bí i Femi Stone
- Nancy Isime gẹ́gẹ́ bí i Kate
- Alex Ekubo gẹ́gẹ́ bí i Obi Wire
- Zubby Michael gẹ́gẹ́ bí i Azaman
- Akah Nnani gẹ́gẹ́ bí i Mario
- Tina Mba gẹ́gẹ́ bí i Mrs Benson
- Blossom Chukwujekwu Officer Dede
- Chigurl gẹ́gẹ́ bí i Amaka
- Yemi Alade gẹ́gẹ́ bí i Mogambe
- Mercy Aigbe
- Ayo Makun gẹ́gẹ́ bí i Dafe
- Timini Egbuson
- Tobi Makinde
- Paschaline Alex Okoli
- Ronya Man
- Esther Kalejaiye gẹ́gẹ́ bí i Omo Joyoibo
- Slimcase
- Ibrahim Yekini
- Femi Jacobs
- Adebayo Salami gẹ́gẹ́ bí i Baba Onibaba
- Shina Peters
- David Jones David
- Martinsfeelz
- Toke Makinwa
- Tega Akpobome (og.tega)
- Naira Marley (cameo appearance)
Ìgbéjáde
àtúnṣeAkindele sọ ọ di mímọ̀ pé kí wọ́n tó bẹ̀rẹ̀ apá kejì fíìmù yìí ní oṣù kejì ọdún 2020, òun ṣe àgbéjáde àwọn àwòrán rẹ̀ àtijọ́ tó yà pẹ̀lú Eniola Badmus. Àwòrán yíyà fún fíìmù náà bẹ̀rẹ̀ ní oṣù February, ọdún 2020[7]. Ètò fíìmù yìí náà tún jẹ́ ìbẹ̀ẹ̀rẹ̀ ìpọwọ́ṣiṣẹ́ pọ̀ òun àti ọkọ rẹ̀ JJC Skillz, gẹ́gé bí olùdarí fíìmù náà[8]. Díẹ̀ lára yíya ìràn fíìmù náà wáyé ní Dubai, United Arab Emirates àti pé àrùn COVID-19 pandemic kó ipa lára fíìmù náà[9].
Àtòjọ àwọn àmì-ẹ̀yẹ
àtúnṣeỌdún | Àmì-ẹ̀yẹ | Ìsọ̀rí | Olùgbà | Èsì | Ìtọ́ka |
---|---|---|---|---|---|
2021 | 17th Africa Movie Academy Awards|Africa Movie Academy Awards | Best Actress in a Leading Role | Funke Akindele | Wọ́n pèé | [10] |
Achievement in Editing | Omo Ghetto | Wọ́n pèé | |||
Best Nigerian Film | Wọ́n pèé | ||||
2022 | 2022 Africa Magic Viewers' Choice Awards|Africa Magic Viewers' Choice Awards | Best Actress in A Comedy | Funke Akindele | Gbàá | [11][12] |
Best Costume Designer | Wọ́n pèé | ||||
Best Actor in A Comedy | Deyemi Okanlawon | Wọ́n pèé | |||
Best Supporting Actress in Movie/ Television Series | Chioma Chukwuka | Wọ́n pèé | |||
Best Make-Up | Abiodun Balogun | Gbàá | |||
Best Picture Editor | JJC Skillz, Valentine Chkukwuma, Adeyemi Shomade | Wọ́n pèé | |||
Best Sound Editor | Puffy Tee | Wọ́n pèé | |||
Best Movie West Africa | Funke Akindele & JJC Skillz | Wọ́n pèé | |||
Best Overall Movie | Wọ́n pèé |
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Top 20 Films Report 9th 15th April 2021". Archived from the original on 20 April 2021. Retrieved 30 August 2021. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Augoye, Jayne (2020-09-08). "Nigeria: Behind-Scene Photos From Funke Akindele's Omo Ghetto 2". allAfrica.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 30 August 2021. Retrieved 2020-12-31. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Funke Akindele returns to street in 'Omo Ghetto: The Saga'". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 26 December 2020. Archived from the original on 31 December 2020. Retrieved 2020-12-31. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Behind-scene photos from Funke Akindele's Omo Ghetto 2" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-09-07. Archived from the original on 17 January 2021. Retrieved 2020-12-31. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Omo Ghetto: The Saga' Becomes Highest-Grossing Nollywood Film of All Time" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-01-26. Archived from the original on 3 February 2021. Retrieved 2021-02-04. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Funke Akindele's "Omo Ghetto (The Saga)" becomes Nollywood's highest-grossing film of all time". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-02-02. Archived from the original on 4 February 2021. Retrieved 2021-02-04. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Funke Akindele is bringing 'Omo Ghetto' back!". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-03-31. Archived from the original on 12 December 2020. Retrieved 2020-12-31. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Teaser: Funke Akindele to co-direct 'Omo Ghetto' (The Saga) with JJC Skillz". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-11-02. Archived from the original on 27 November 2020. Retrieved 2020-12-31. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Funke Akindele's 'Omo Ghetto' Saga Continues". THISDAYLIVE (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-12-05. Archived from the original on 3 January 2021. Retrieved 2020-12-31. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Banjo, Noah (2021-10-29). "FULL LIST: Ayinla, Omo Ghetto: The Saga bag multiple nominations at AMAA 2021". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-10-30. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "2022 Africa Magic Awards Nominees don land- See who dey list". BBC News Pidgin. https://www.bbc.com/pidgin/tori-60818021.
- ↑ "Stan Nze, Osas Ighodaro win big - Full list of all di winners from 2022 AMVCA". BBC News Pidgin. https://www.bbc.com/pidgin/tori-61452928.