Halle (akorin)
Halle (orúkọ àbísọ rẹ̀ ni Halle Grace Ihmordu; a bi ní ọjọ́ Kẹtàdínlọ́gún oṣù Kejìlá) jẹ́ òṣèrébìnrin, akọrin, àti oníjó ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí ó ń ṣiṣẹ́ fún N3rd Records.
Halle | |
---|---|
Orúkọ àbísọ | Halle Grace Ihmordu |
Wọ́n tún mọ̀ọ́ bíi | Halle |
Ọjọ́ìbí | Ìpínlẹ̀ Edo, Nàìjíríà |
Irú orin | Orin Afro pop music, Reggae, dancehall |
Occupation(s) | Akọrin |
Years active | 2004–present |
Labels | N3rd Records theMedia 360 Company |
Associated acts |
|
Website | hallemordu.com |
Iṣẹ́ rẹ̀
àtúnṣeNí ọdún 2008, ó ṣeré fún ìgbà àkọ́kọ́ nínú fíìmù Relentless (2008–2009), wọ́n padà ṣe àgbéjáde fíìmù náà ní BFI London Film Festival ní ọdún 2010.[1] Èyí ni fíìmù àkọ́kọ́ tí ó ti ṣeré; àwọn òṣèré tí ó tún wà nínú fíìmù náà ni Gideon Okeke, Nneka Egbuna, Jimmy Jean-Louis àti Tope Oshin Ogun.
Kí ó tó di òṣèrébìnrin, Halle, ma ń jó, ó ti jó ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìdíje ìjọ́, ó sì jáwé olúborí ní àwọn ìdíje bi ìdíje Channel O Dance Africa, àti the last female standing ní Maltina Dance Hall (ọdún 2008). Ní ọdún 2012, ó ṣe àgbéjáde orin àkọ́kọ́ rẹ̀, Falling in Love, ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn sì gba ti orin náà.
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Akideinde, Oye (October 6, 2010). "360Trailers: "Relentless" starring Jimmy Jean-Louis, Gideon Okeke, Halle Mordu & Nneka Egbuna". 360Nobs.com. Archived from the original on July 14, 2018. Retrieved October 4, 2014. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)