Hamid Karzai
Hamid Karzai (Pashto: حامد کرزی - Ḥāmid Karzay; ọjọ́ìbí: Ọjó kẹrìnlélógún Oṣù kejìlá Ọdún 1957) jẹ́ Ààrẹ orílè-èdè Afghanistan fún bí ọdún mẹwá, lati Ọjọ́ keje Oṣù kẹjìlá Ọdún 2004 di Ọjọ́kàndínlọ́gbọ̀n Oṣù kẹsán Ọdún 2014.[1]
Hamid Karzai حامد کرزی | |
---|---|
Ààrẹ ilẹ̀ Afghanístàn | |
In office 22 December 2001 – 29 September 2014 Acting: 22 December 2001 – 13 July 2002 | |
Vice President | Hedayat Amin Arsala Mohammed Fahim Nematullah Shahrani Karim Khalili Abdul Qadir Ahmad Zia Massoud Yunus Qanuni |
Asíwájú | Burhanuddin Rabbani |
Arọ́pò | Ashraf Ghani |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 24 Oṣù Kejìlá 1957 Karz, Kandahar, Afghanistan |
Ọmọorílẹ̀-èdè | Afghan |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Independent |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Zeenat Karzai (1999–present) |
Àwọn ọmọ | Mirwais Malalai Howsi |
Alma mater | Himachal Pradesh University |
Website | Hamid Karzai.com |
Àwọ́n Itọ́kasí
àtúnṣe- Dam, Bette. A Man and a Motorcycle, Ipso Facto Publ., Sept. 2014.
- Dam, Bette. "The Misunderstanding of Hamid Karzai", Foreign Policy, Oc.t 3, 2014.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
àtúnṣe- ↑ Matthew J. Morgan (2007). A Democracy is Born: An Insider's Account of the Battle Against Terrorism in Afghanistan. Praeger Security International. ISBN 978-0-275-99999-5. http://books.google.com/books?id=k35uAAAAMAAJ.