Ashraf Ghani
Olóṣèlú
Ashraf Ghani (Pashto/Àdàkọ:Lang-prs; ọjọ́ìbí 19 May 1949) ni olóṣèlú ará Afghanístàn tó wà nípò gẹ́gẹ́ bíi Ààrẹ ilẹ̀ Afghanístàn lọ́wọ́lọ́wọ́. Wọ́n kọ́kọ́ dìbòyàn ní 20 September 2014, wọ́n sì tún tún-dìbòyàn ní 28 September 2019. Ghani jẹ́ onímọ̀ ìdá-ènìyàn, tẹ́lẹ̀ ó siṣẹ́ bíi Alákóso Ètò Ìṣúná àti bíi Kánsélọ̀ Yunifásítì Kabul.
Ashraf Ghani | |
---|---|
اشرف غني | |
Ghani in 2018 | |
President of Afghanistan | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 29 September 2014 | |
Vice President | Amrullah Saleh Sarwar Danish Abdul Rashid Dostum |
Asíwájú | Hamid Karzai |
Chancellor of Kabul University | |
In office 22 December 2004 – 21 December 2008 | |
Asíwájú | Habibullah Habib |
Arọ́pò | Hamidullah Amin |
Minister of Finance | |
In office 2 June 2002 – 14 December 2004 | |
Ààrẹ | Hamid Karzai |
Asíwájú | Hedayat Amin Arsala |
Arọ́pò | Anwar ul-Haq Ahady |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Ashraf Ghani Ahmadzai 19 Oṣù Kàrún 1949 Logar, Afghanistan |
Ọmọorílẹ̀-èdè | Afghan[1] American (before 2009) |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Independent |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Rula Ghani |
Ẹbí | Hashmat Ghani Ahmadzai (brother) |
Àwọn ọmọ | Mariam Tariq |
Alma mater | American University of Beirut Columbia University Kabul University |
Nickname(s) | Baba |
Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedaspistrategist.org.au