Ààrẹ ilẹ̀ Afghanístàn

(Àtúnjúwe láti President of Afghanistan)

Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Olómìnira Onímàle ilẹ̀ Afghanístàn ni olórí orílẹ̀-èdè àti olórí ìjọba ilẹ̀ Afghanístàn. Ààrẹ lọ́wọ́lọ́wọ́ ni Ashraf Ghani.

Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Olómìnira Onímàle ilẹ̀ Afghanístàn
President of the Islamic Republic of Afghanistan

د افغانستان د اسلامي جمهوریت رئیس نوماند
نامزد رئيس جمهوری اسلامی افغانستان
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ashraf Ghani

since 29 September 2014
StyleThe Honourable (Formal)
His Excellency (Diplomatic)
ResidencePresidential Citadel, Kabul, Afghanistan
AppointerDirect election
Iye ìgbàỌdún márùún, renewable once
Ẹni àkọ́kọ́Mohammed Daoud Khan (Republic)
Hamid Karzai (Islamic Republic)
Formation17 July 1973 (Republic)
7 December 2004 (Islamic Republic)
DeputyVice President of Afghanistan
Owó osù960,000 AFN per month[1]
WebsiteOffice of the President

Kí wọn ó tó ṣe ìdásílẹ̀ ipò ààrẹ Orílẹ̀-èdè Olómìnira Onímàle ilẹ̀ Afghanístàn ní 2004, Afghanístàn tilẹ̀ ti jẹ́ Orílẹ̀-èdè olómìnira onímàle láti àrin ọdún 1973 àti 1992 àti láti ọdún 2001 ṣíwájú. Kí ó tó di ọdún 1973, ibẹ̀ jẹ́ mímọ̀ bíi ilẹ̀ọba. Ní àrin ọdún 1992 àti 2001, nígbà ogun abẹ́lé, Afghanístàn jẹ́ mímọ́ bíi Orílẹ̀-èdè Onímàle ilẹ̀ Afghanístàn, àti lẹ́yìn náà bíi Ẹ́míráti Onímàle ilẹ̀ Afghanístàn.


Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe