Hassanat Akínwandé
Òṣéré orí ìtàgé
Hassanat Táíwò Akínwándé, tí wọ́n bí ní ọjọ́ Kejìlélógún oṣù Kejì ọdún 1960, tí a mọ̀ sí stage name Wùnmí, jẹ́ gbajú-gbajà òṣèré orí-ìtàgé tí ó ti kópa nínú eré ati sunimá oríṣiríṣi. [1]
Iṣẹ́ rẹ̀
àtúnṣeÓ bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ ré gẹ́gẹ́ bí òṣèré orí-ìtàgé ní ọdún 1980 nígbà tí ó kópa nínú eré onípele ti ọlọ́sọ̀ọ̀sẹ̀ tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ Fèyí Kọ́gbọ́n.[1] She has had leading roles in over 50 videos.[1] Ìròyìn gbe wípé wọ́n fi ẹ̀sùn ìgbé egbògi olóró kàn án ní ọdún 2006. Awuye-wuye yí túbọ̀ mú kí òkìkí rẹ̀ tún kàn siwájú si. [2][1]Lára àwọn òṣèré tí wọ́n jọ wà ní sàwáwù ni Taiwo Hassan, Ẹ̀bùn Olóyèdé Ọlá-Ìyá tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Igwe, Yínká Quadri àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ 1.0 1.1 1.2 1.3 Drug disgrace for Nollywood star[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́] Senan Murray, BBC News website, 29 Nov 06; accessed 15 September 2007
- ↑ Drug disgrace for Nollywood star[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́] Vanguard Posted to the Web: Friday, November 24, 2006