Helen Esuene

Oloselu Naijiria

Helen Esuene (bíi ní Oṣù kọkànlá Ọdún 1949) jẹ́ òṣìṣẹ́ ìjọba Nàìjíríà tẹ́lẹ̀ tí wọ́n yàn gẹ́gẹ́ bí mínísítà ìpínlẹ̀ fún ètò ìlera[1], tí wọ́n tún padà yàn gẹ́gẹ́ bíi mínísítà fún ètò àyíká àti ilé ní ìjọba Ààrẹ Olusegun Obasanjo láti ọdún 2005 sí 2007.[2] Ó jẹ́ aṣojú ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin láti Ọdún 2011 sí Ọdún 2015 lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú People's Democratic Party.[3]

Helen Esuene
Mínísítà Ìpínlẹ̀ Fún Ètò Ìlera
In office
Oṣù keje Ọdún 2005 – Oṣù kínín Ọdún 2006
Mínísítà Ìpínlẹ̀ Fún Ètò Àyíká
In office
Oṣù kínín Ọdún 2006 – Oṣù kínín Ọdún 2007
AsíwájúIyorchia Ayu
Mínísítà Ìpínlẹ̀ Fún Ètò Àyíká àti Ilé
In office
Oṣù kínín Ọdún 2007 – Oṣù karún Ọdún 2007
AsíwájúRahman Mimiko (Ilé)
Arọ́pòHalima Tayo Alao
Aṣojú Gúúsù Akwa Ibom ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà
In office
Oṣù kẹrin Ọdún 2011 – Oṣù karún Ọdún 2015
AsíwájúEme Ufot Ekaette
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbíOjọ́ kẹtàlélógún Oṣù kọkànlá Ọdún 1949

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "As Obasanjo Reshuffles Cabinet... Ministers Under Probe for Corruption". BNW News. July 14, 2005. Archived from the original on 2012-01-11. Retrieved 2010-02-24. 
  2. KABIRU YUSUF (January 11, 2007). "Obasanjo reshuffles cabinet...Swears-in 6 new ministers". Daily Triumph. Retrieved 2010-02-24. 
  3. EMMANUEL CHIDIOGO (April 11, 2011). "PDP sweeps Akwa-Ibom". Daily Times. Retrieved 2011-04-21.