Heloísa Jorge (ti won bi ni ojo kini osu keje odun 1984) je osere ati oludari ere ti o wa lati ilu Àngólà

Heloísa Jorge
Ọjọ́ìbíOṣù Keje 1, 1984 (1984-07-01) (ọmọ ọdún 39)
Chitato
Orílẹ̀-èdèAngolan
Iléẹ̀kọ́ gígaFederal University of Bahia
Iṣẹ́Osere, Oludari
Ìgbà iṣẹ́2012-titi di isinyin

Igbesiaye àtúnṣe

Won bi si Chitato ni Lunda Norte Province. Baba re je omo orile ede Brasil iya re si wa lati ilu Angola. Ojuwe ara e gege bi eyan kan ti oju man ti ni igba ti owa ni omode.[1]Ni igba ti o wa ni omo odun mejila ohun ati awon molebi re ko lo si ilu Brasil nitori Ogun Abele Angola, win gbe ni ilu Montes Claros.[2] Jorge bere eko imo thearter ni ile eko, osi darapo mo egbe wan. Ni igba ti o se idanwo ati wole si ile eko giga Brasil ni omo odun mejidinlogun, o gbero lati ko eko sise aworan. O ko lo si ilu Salvador, Bahia lati lo si ile eko giga titi Bahia[3]

Ni igba ti on ko eko ere ori itage, Jorge bere si ni ko awon iwa ironu awujo osi fi kun igberaga ara eni ti ti . Ni odun 2007 won fi oruko re sile fun Ami eye Braskem nitori ipa re ninu ere O Dia 14, Ângelo Flávio ni o dari ere na. Pelu ni odun 2007, Jorge ko ere Uma Mulher Vestida de Sol, lati bu iyi fun Ariano Suassuna.[4]O ja de ile eko giga ni odun 2008.[5] Ni odun 2009, wan tun fi oruko Jorge kale fun ami eye Braskem fun ipa re ninu A Farsa da Boa Preguiça, ti oludari re je Harildo Deda.[6] O pada si Angola ni odun 2009 pelu egbe itage e, won se ere Amêsa ti José Mena Abrantes ko.[7]

Ni odun 2012, Jorge ko ipa Fabiana ninu jara ti akori e je Gabriela.[8][9] Won pe ki o wa dara po mo jara Angola Jikulumessu, eleyi ti o se agbega fun awon eniyan alawo dudu ni odun 2014. Ni odun kan na, Jorge se alejo eto Globo International Connections program.[10] Ni odun 2016, o se eru Luanda nini eto Liberdade. O tun ko ipa iya ti ofe ku ti oruko re je Gilda Cunha Matheus ninu jara A dona do pedaco.[11]

Awon Asayan Ere àtúnṣe

Tẹlifisiọnu àtúnṣe

Odun Akọle Ipa Awọn akọsilẹ
2012 Gabriela Fabiana
Ọdun 2014 Jikulumessu Djamila Pereira
2016 Liberdade, Liberdade Luanda dos Santos
2017 A Lei ṣe Amori Laura Correia da Silva Awọn iṣẹlẹ: "16 de janeiro – 31 de março" [12]
2017-18 Sob Pressão Jaqueline Vaz Awọn akoko 1-2
2019 A Dona ṣe Pedaço Gilda Cunha Matheus

Awọn fiimu àtúnṣe

Odun Akọle Ipa Awọn akọsilẹ
2015 Se te Queres Matar, Mata-te
2017 Casca de Baobá Maria
2018 Bate Coração Dokita Claudia
TBA Sujeito Oculto

Awọn itọkasi àtúnṣe

  1. André, Fabiana (15 June 2016). "Heloisa Jorge". Rede Angola (in Portuguese). Retrieved 15 October 2020. 
  2. Ribeiro, Naiana (31 August 2019). "Baiana de coração, Heloisa Jorge fala sobre morte de Gilda em A Dona do Pedaço". Correio (in Portuguese). Retrieved 15 October 2020. 
  3. André, Fabiana (15 June 2016). "Heloisa Jorge". Rede Angola (in Portuguese). Retrieved 15 October 2020. 
  4. Ribeiro, Naiana (31 August 2019). "Baiana de coração, Heloisa Jorge fala sobre morte de Gilda em A Dona do Pedaço". Correio (in Portuguese). Retrieved 15 October 2020. 
  5. André, Fabiana (15 June 2016). "Heloisa Jorge". Rede Angola (in Portuguese). Retrieved 15 October 2020. 
  6. Ribeiro, Naiana (31 August 2019). "Baiana de coração, Heloisa Jorge fala sobre morte de Gilda em A Dona do Pedaço". Correio (in Portuguese). Retrieved 15 October 2020. 
  7. André, Fabiana (15 June 2016). "Heloisa Jorge". Rede Angola (in Portuguese). Retrieved 15 October 2020. 
  8. Rodrigues, Thayná (29 January 2017). "Heloisa Jorge, no ar em ‘A lei do amor’, posa para ensaio de moda com tons terrosos". Extra (in Portuguese). Infoglobo. Retrieved 15 October 2020. 
  9. Mafrans, Paulo Víctor (8 May 2016). "Heloisa Jorge, a escrava Luanda da trama das 11, chegou ao Brasil refugiada de guerra". Extra (in Portuguese). Infoglobo. Retrieved 15 October 2020. 
  10. Ribeiro, Naiana (31 August 2019). "Baiana de coração, Heloisa Jorge fala sobre morte de Gilda em A Dona do Pedaço". Correio (in Portuguese). Retrieved 15 October 2020. 
  11. "Entenda a trama de 'A Dona do Pedaço', próxima novela das 9, que traz Juliana Paes e Marcos Palmeira como casal protagonista" (in Portuguese). Globo.com. 24 February 2019. Retrieved 15 October 2020. 
  12. Empty citation (help) 

Awọn ọna asopọ ita àtúnṣe