Àngólà, lóníbiṣẹ́ bíi Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Àngólà (Pọrtugí: República de Angola, pípè [ʁɨˈpublikɐ dɨ ɐ̃ˈɡɔla];[4] Kikongo, Kimbundu, Umbundu: Repubilika ya Ngola), jẹ́ orílẹ̀-èdè kan ní apágúsù Áfríkà tó ní bodè mọ́ Namibia ní gúsù, Orílẹ̀-èdè Olómìnira Olóṣèlú ilẹ̀ Kóngò ní àríwá, àti Zambia ní ilàòrùn; ìwọ̀òrùn rẹ̀ bọ́ sí etí Òkun Atlántíkì. Luanda ni olúìlú rẹ̀. Ìgbèríko òde Kàbíndà ní bodè mọ́ Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Kóngò àti Orílẹ̀-èdè Olómìnira Olóṣèlú ilẹ̀ Kóngò.

Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Àngólà
Republic of Angola

República de Angola  (Portuguese)
Repubilika ya Ngola   (Kikongo, Kimbundu, Umbundu)
'Orin ìyìn: Angola Avante!  (Portuguese)
Rìnsó Àngólà

Forward Angola!
Location of Àngólà
OlùìlúLuanda
Ìlú tótóbijùlọolúìlú
Àwọn èdè ìṣẹ́ọbaPotogí
Lílò national languagesKikongo, Chokwe, Umbundu, Kimbundu, Ganguela, Kwanyama
Àwọn ẹ̀yà ènìyàn
(2000)
37% Ovimbundu
25% Ambundu
13% Bakongo
22% ará Áfríkà míràn
2% Mestiço
1% ará Europe
Orúkọ aráàlúará Àngólà
ÌjọbaOrílẹ̀-èdè olómìnira ìṣọ̀kan oníàrẹ
• Ààrẹ
João Lourenço
Bernito de Sousa
AṣòfinIlé Ìgbìmọ̀ Aṣòfin
Ìlómìnira
• látọwọ́ Pọ́rtúgàl
11 November 1975
Ìtóbi
• Total
1,246,700 km2 (481,400 sq mi) (23k)
• Omi (%)
negligible
Alábùgbé
• 2014 census
25,789,024[1]
• Ìdìmọ́ra
20.69/km2 (53.6/sq mi) (199th)
GDP (PPP)2011 estimate
• Total
$115.679 billion[2] (64k)
• Per capita
$5,894[2] (107k)
GDP (nominal)2011 estimate
• Total
$100.948 billion[2] (61st)
• Per capita
$5,144[2] (91k)
Gini (2000)59[3]
Error: Invalid Gini value
HDI (2011)0.486
Error: Invalid HDI value · 148k
OwónínáKwanza (AOA)
Ibi àkókòUTC+1 (WAT)
• Ìgbà oru (DST)
UTC+1 (kòsí)
Ojúọ̀nà ọkọ́ọ̀tún
Àmì tẹlifóònù+244
ISO 3166 codeAO
Internet TLD.ao

Àngólà di ileamusin Portugal ni 1884 leyin Ipade Berlin. O gba ilominira ni odun 1975 leyin ogun itusile. Ko pe leyin ilominira ni ogun abele sele lati 1975 de 2002. Àngólà ni opo alumoni ati petroliomu, be sini okowo re ti ungbera soke pelu iwon eyoika meji lati odun 1990, agaga lateyin igba ti ogun abele wa sopin. Sibesibe opagun ijaye si kere gidigidi fun opo alabugbe, be sini ojo ori ati iye ọ̀fọ̀ ọmọwọ́ ni Angola je awon eyi to buru julo lagbaye.[5]

Jeografi

àtúnṣe

Àwọn ìtokasi

àtúnṣe
  1. Governo de Angola - page 89
  2. 2.0 2.1 2.2 2.3 "Angola". International Monetary Fund. Retrieved 17 April 2012. 
  3. "Gini Index". World Bank. Retrieved 2 March 2011. 
  4. This is the pronunciation in Portugal; in Angola it is pronounced as it is written
  5. (Gẹ̀ẹ́sì) Life expectancy at birth Archived 2018-12-29 at the Wayback Machine. www.cia.gov (2009)