Ekenedirichukwu Ijemba (tí wọ́n bí ní May 14, 1991), tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ sì ń jẹ́ Humblesmith, jẹ́ olórin afropop ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, tó di gbajúmọ̀ ní ọdún 2015, lẹ́yì tó ṣàgbéjáde orin rẹ̀, tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ "Osinachi". [1][2][3]

Humblesmith
Background information
Orúkọ àbísọEkenedirichukwu Ijemba
Ọjọ́ìbí14 Oṣù Kàrún 1991 (1991-05-14) (ọmọ ọdún 33)
Abakaliki, Ebonyi State, Nigeria
Ìbẹ̀rẹ̀Imo State, Nigeria
Irú orinR&B, afropop, highlife
Occupation(s)singer-songwriter, vocalist
InstrumentsVocals
Years active2011–present
LabelsShow Bobo Music
Associated acts

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Ayodele Johnson (July 23, 2016). "Humblesmith: 'I want to give $2000 to my fans', singer says". Pulse Nigeria. http://pulse.ng/celebrities/humblesmith-i-want-to-give-2000-to-my-fans-singer-says-id5298860.html. Retrieved July 24, 2016. 
  2. "Humblesmith speaks on background". Naij. April 4, 2016. https://www.naij.com/787769-used-hawk-moi-moi-traffic-popular-singer-reveals.html. Retrieved July 24, 2016. 
  3. Chijioke5050 (December 16, 2020). "Humblesmith Attracta ft. Tiwa Savage". Naijabeatz. Archived from the original on July 11, 2023. https://web.archive.org/web/20230711042706/https://naijabeatz.com.ng/humblesmith-attracta-ft-tiwa-savage/2079/. Retrieved January 7, 2021.