Ibrahim Tahir
Olóṣèlú
Talba Ibrahim Tahir | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Ibrahim Tahir Tafawa Balewa, Northern Region, British Nigeria |
Aláìsí | December 8, 2009 Cairo, Egypt, |
Iléẹ̀kọ́ gíga | BA (sociology) PhD (social anthropology) King's College, Cambridge |
Iṣẹ́ | Sociologist, writer, politician |
Gbajúmọ̀ fún | Traditionalist conservatism |
Notable work | The Last Imam (1980) |
Ibrahim Tahir (tí ó kú lọ́jọ́ kẹsàn-án oṣù Kejìlá ọdún 2009) jẹ́ onímọ̀ àyíká (sociologist), oǹkọ̀wé àti òṣèlú ọmọ orílẹ̀-èdè ní ètò-òṣèlú ẹlẹ́ẹ̀kejì Nigeria. Bákan náà, ó jẹ́ ọ̀kan gbòógì nínú ẹgbẹ́ alákatakítí Kaduna mafia. Kí ó tó dárapọ̀ mọ́ òṣèlú, ó jẹ́ onímọ̀ àyíká tí ó gbajúmọ̀ nínú òye Traditionalist conservative.[1]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Haruna, Mohammed. "Tahir: The Death of a Radical Conservative". Gamji.com.