Ijebu Ode Grammar School
Ijebu Ode Grammar School (JOGS) jẹ́ ilé-ìwé girama fún àwọn ọmọkùnrin nìkan tí ó wà ní Ìjẹ̀bú-Òde, ní apá Gúúsù mọ́ Ìwọ̀-Oòrùn ilẹ̀ Nàìjíríà.[1] Wọ́n ṣe ìdásílẹ̀ ilé-ìwẹ́ yìí ní 20 January ọdún 1913, ilé-ìwé náà jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ilé-ìwé tí ó pẹ́ jù lọ ní orílẹ̀-èdẹ̀ Nàìjíríà.[2][3]
Àwọn ilé
àtúnṣe- Gansallo (Blue) House
- Johnson (Red) House
- Kuti (White) House
- Odumosu (Green) House
- Phillips (Yellow) House
- School (Purple) House
Àwọn ènìyàn tó lààmilaaka ní ilé-ìwé náà
àtúnṣe- Abraham Adesanya, agbẹjọ́rò àti ajìjàgbaara ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà
- Inumidun Akande
- Mobolaji Bank Anthony
- Deji Ashiru Onímọ̀-ẹ̀rọ àti engineer MD/CEO ti Ogun-Osun River Basin Development Authority
- George Ashiru Akọ́ṣẹ́mọṣẹ́Taekwondo grandmaster
- Harold Demuren
- Bode George olóṣèlú ní Nàìjíríà
- Seth Kale
- Adeleke Mamora mínísítà tó ń rí sí ètò ìlera
- Omololu Meroyi, sẹ́natọ̀ ti Ondo South constituency
- Adeola Odutola oníṣòwò
- Olu Oyesanya akọ̀ròyìn
- Vector olórin
- Wizkid olórin
Àwọn ẹ̀ka tó gbajúmọ̀
àtúnṣeOld Students Association
àtúnṣeIjebu-Ode Grammar School ní ìgbìmọ̀ àwọn akẹ́kọ̀ọ́ tó ti kékọ̀ọ́ gboyè ní ilé-ìwé náà, tí wọ́n ń pè ní JOGSOBA (Jebu-Ode Grammar School Old Boys Association)
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Emmanuel Ayankanmi Ayandele (1992). The Ijebu of Yorubaland, 1850-1950: politics, economy, and society. Heinemann Educational Books (Nigeria). ISBN 978-978-129-433-4. https://books.google.com/books?id=MnUuAQAAIAAJ.
- ↑ Ukwu, Jerrywright (2015-05-22). "Nigeria's Ancient Secondary Schools". http://www.naij.com/444344-nigerias-ancient-secondary-schools.html. Retrieved 2016-02-25.
- ↑ Barbara Goff (9 May 2013). 'Your Secret Language': Classics in the British Colonies of West Africa. A&C Black. pp. 48–. ISBN 978-1-78093-205-7. https://books.google.com/books?id=QUBMAQAAQBAJ&pg=PA48.