Ilẹ̀ọba Aṣọ̀kan

(Àtúnjúwe láti Ilẹ̀ọba Àparapọ̀)

Ilẹ̀ọba Aṣọ̀kan Brítánì Olókìkí àti Írẹ́lándì Apáàríwá ti a mo si Ilẹ̀ọba Aṣọ̀kan, UK tabi Britani jẹ́ orílẹ̀-èdè ní Europe. Nínú bodè rẹ̀ ni a ti rí erékùsù Brítánì Olókìkí, apá ìlàoòrùn-àríwá erékùsù Irẹlandi àti ọ̀pọ̀ àwọn erékùsù kékéèké. Irẹlandi Apáàríwá nìkan ni apá Ilẹ̀ọba Ìsọ̀kan tó ní bodè mọ́ oríilẹ̀ pẹ̀lú Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Irẹlandi.

Ilẹ̀ọba Aṣọ̀kan Brítánì Olókìkí àti Írẹ́lándì Apáàríwá
United Kingdom of Great Britain and Northern Ireland[1]

Motto: ["Dieu et mon droit"] error: {{lang}}: text has italic markup (help)[2]  (French)
"God and my right"
Orin ìyìn: "God Save the King"[3]
Ibùdó ilẹ̀  Ilẹ̀ọba Aṣọ̀kan  (dark green) – on the European continent  (light green & dark grey) – in Isokan Europe  (light green)
Ibùdó ilẹ̀  Ilẹ̀ọba Aṣọ̀kan  (dark green)

– on the European continent  (light green & dark grey)
– in Isokan Europe  (light green)

Olùìlú
àti ìlú tótóbijùlọ
London
Àwọn èdè ìṣẹ́ọbaEnglish[4]
Lílò regional languagesWelsh, Irish, Ulster Scots, Scots, Scottish Gaelic, Cornish[5]
Àwọn ẹ̀yà ènìyàn
(2001)
92.1% White,
4.00% South Asian, 2.00% Black, 1.20% Mixed Race, 0.80% East Asian and Other
Orúkọ aráàlúBritish, Briton
ÌjọbaParliamentary system and Constitutional monarchy
• Monarch
Charles III
Keir Starmer
AṣòfinParliament
House of Lords
House of Commons
Formation
1 May 1707
1 January 1801
12 April 1922
Ìtóbi
• Total
244,820 km2 (94,530 sq mi) (79th)
• Omi (%)
1.34
Alábùgbé
• mid-2006 estimate
60,587,300[1] (22nd)
• 2001 census
58,789,194[2]
• Ìdìmọ́ra
246/km2 (637.1/sq mi) (48th)
GDP (PPP)2006 estimate
• Total
US$2.270 trillion (6th)
• Per capita
US$37,328 (13th)
GDP (nominal)2007 estimate
• Total
$2.772 trillion (5th)
• Per capita
US$45,845 (9th)
Gini (2005)34[3]
Error: Invalid Gini value
HDI (2005) 0.946
Error: Invalid HDI value · 16th
OwónínáPound sterling (£) (GBP)
Ibi àkókòUTC+0 (GMT)
• Ìgbà oru (DST)
UTC+1 (BST)
Àmì tẹlifóònù44
Internet TLD.uk [6]

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "UK population grows to 60.6 million". Population Estimates. Office for National Statistics. 2007-08-22. Retrieved 2007-08-22. In mid-2006 the resident population of the UK was 60,587,000. The UK population has increased by 8 per cent since 1971, from 55,928,000. 
  2. Population Estimates at www.statistics.gov.uk
  3. CIA World Factbook Archived 2009-05-13 at the Wayback Machine.[Gini rankings]