Ime Bishop Umoh

Òṣéré orí ìtàgé

Ime Bishop, tí wọ́n tún pè níOkon Lagos tàbí Udo Yes, jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé , aláwàdà ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Nigeria.

Ime Bishop
Ọjọ́ìbíIme Bishop Umoh
15 July 1981
Nsit Ibom, Akwa Ibom State
Orílẹ̀-èdèNigerian
Orúkọ mírànOkon Lagos
Iléẹ̀kọ́ gígaUniversity Of Uyo
Iṣẹ́actor, comedian
Olólùfẹ́Àdàkọ:Married
Àwọn ọmọ(2)

ìbẹ̀ré ayé àti iṣẹ́ rẹ̀

àtúnṣe

Ime jẹ́ ọmọ bíbí agbègbè Nsit Ibom àti ẹ̀yà Ìbíòbíó láti Ìpínlẹ̀ Akwa Ibom. Ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ Yunifásitì Uyo níbi tí ó ti kẹ́kọ̀ọ́ gboyè nínú ẹ̀kọ́ philosophy. Ó ti bẹ̀rẹ̀ síṣe eré orí-ìtàgé láti ìgbà tí ó yo wà ní ọmọdé, lẹ́yìn tí ó ti dara pọ̀ mọ́ Nollywood ó ti kópa nínú eré tí ó ti tó ọgọ́rùn ún. Eré tí ó gbe ìràwọ rẹ̀ jáde ni Uyai, eré tí ọ̀gbẹ́ni Emem Isong gbé jáde ní ọdún 2008. [1][2]

Ìfọwọ́ sí rẹ̀

àtúnṣe

Ìyànsípò ìṣèlú rẹ̀

àtúnṣe

Wọ́n yan Ime sí ipò olùdámọ̀ràn pàtàkì sí Gómìnà Ìpínlẹ̀ Akwa Ibom, ìyẹn Udom Gabriel Emmanuel lórí ìlanilọ́yẹ̀ fún ará ìlú.[4]

Àwọn amì-ẹ̀yẹ àti ìfisọ́rí rẹ̀

àtúnṣe
Ọdún Ayẹyẹ Ẹ̀bùn Ẹni tí ó gbàá Èsì
2012 2012 Best of Nollywood Awards Comedy Movie of the year Okon lagos 2 Gbàá
2013 2013 Best of Nollywood Awards Comedy of the year Okon goes to school Gbàá
2013 2013 Nollywood Movies Awards Best Actor in Supporting Role Udeme Mmi Gbàá
2014 2014 Best of Nollywood Awards Best Comedy of the year I come lagos Gbàá
2016 2016 Nigeria Teen Choice Awards Comic Actor of the year(English) [5] Wọ́n pèé
2016 2016 Africa Magic Viewers Choice Awards Best Actor in a comedy Caught in the Act Wọ́n pèé
2017 2017 Africa Magic Viewers Choice Awards Best Actor In Comedy The Boss is Mine Gbàá

Àwọn àṣàyàn eré rẹ̀

àtúnṣe
Àkọ́lé Ọdún
Uyai 2008
Edikan 2009
Silent Scandals 2009
The Head Office 2011
Vulcanizer 2011
Okon Lagos 2011
Udeme mmi 2012
Okon goes to school 2012
Sak Sio 2012
Jump and pass 2013
The place 2013
The champion
Okon the driver 2014
Okon on the run 2014
Okon and Jennifer 2015
Udo Facebook 2015
The Boss Is Mine 2016
Lost In London 2017
Unroyal 2020

Ime kópa nínú fọ́nrán fídíò kan tí wọ́n oè ní Pregnant Man lẹ́yìn tí ìsémọ́lé ajàkálẹ̀ àrùn COVID-9 rọlẹ̀ díẹ̀.[6]

Ẹ tún wo

àtúnṣe

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe

Ìtàkùn ìjásóde

àtúnṣe

Àdàkọ:IMDb name Ime Bishop Umoh lórí Twitter


Àdàkọ:Authority control

Àdàkọ:Nigeria-actor-stub