Udom Gabriel Emmanuel
Olóṣèlú
Udom Gabriel Emmanuel (ojoibi 11 July 1966) ni gomina Ipinle Akwa Ibom ni Naijiria, o wa lori aga lati 29 May 2015 leyin igbatowe leyin idibo April 2015 labe egbe oloselu People's Democratic Party. Won tun tundiboyan sipo gomina ni ojo 29k osu karun odun 2019.[1]
Udom Gabriel Emamanuel | |
---|---|
4th Governor of Akwa Ibom State | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 29 May 2015 | |
Deputy | Moses Ekpo |
Asíwájú | Godswill Akpabio |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 11 Oṣù Keje 1966 Awa Iman, Onna LGA, Akwa Ibom State, Nigeria |
Ọmọorílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | PDP |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Martha Udom |
Àwọn òbí | Gabriel Emmanuel Nkenang |
Alma mater | University of Lagos
|
Website | mrudomemmanuel.com |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Kinsmen Celebrate Governor Udom Emmanuel With Inaugural Reception". Retrieved 9 October 2016.