Iru (food)
Àyọkà yi ni opo oran. Jọwọ ran lowolati ṣe àtúnṣe tabi soro nipa isoro re lori ọ̀rọ̀. (Learn how and when to remove these template messages)
|
Àdàkọ:Other Irú (Yoruba) tàbí Dawadawa (Hausa) or Eware (Edo) tàbí Sumbala (Bambara) tàbí Narghi (Fula) jẹ́ irúfẹ́ oúnjẹ tí a fi irú (Parkia biglobosa) tí ó ti pẹ́, tàbí kan ṣe tí a sì máa ń lò bíi ara èròjà ìdáná.[1] Ó súnmọ́ Ògìrì tàbí douchi ní jíjọ. Ó gbajúmọ̀ nínú àwọn oúnjẹ Ìwọ̀ oòrùn Áfíríkà. A máa ń lò ó fún síse àwọn ọbẹ̀ ìbílẹ̀ bíi ọbẹ̀ ẹgúsí, ọbẹ̀ ilá, ọbẹ̀ ewédú, àti ọbẹ̀ ọ̀gbọ̀nọ̀.[2]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Dawadawa: The Magical Food Ingredient". LivingTheAncestralWay (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2024-10-23.
- ↑ Petrikova, Ivica; Bhattacharjee, Ranjana; Fraser, Paul D. (Jan 2023). "The 'Nigerian Diet' and Its Evolution: Review of the Existing Literature and Household Survey Data". Foods 12 (3): 443. doi:10.3390/foods12030443. PMC 9914143. PMID 36765972. //www.pubmedcentral.nih.gov/articlerender.fcgi?tool=pmcentrez&artid=9914143.