Jennifer Hudson
Jennifer Hudson je osere lóbinrin ati akọrin to gba Ebun Akademi bi Obinrin Osere Keji Didarajulo[1].
Jennifer Hudson | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Jennifer Kate Hudson 12 Oṣù Kẹ̀sán 1981 Chicago, Illinois, U.S. |
Ẹ̀kọ́ | Langston University Kennedy-King College |
Iṣẹ́ |
|
Ìgbà iṣẹ́ | 2004–present |
Works |
|
Alábàálòpọ̀ |
|
Àwọn ọmọ | 1 |
Awards | List of awards and nominations received by Jennifer Hudson |
Musical career | |
Irú orin | |
Instruments | Vocals |
Years active | 2006–present |
Labels |
|
Associated acts | Ne-Yo |
Website | jenniferhudson.com |
Ìgbèsi Àràbinrin naa
àtúnṣeHudson ni a bini óṣù september ọdun 1981 ni Chicago, Illinois. Jennifer ni a tọ ni ilana Baptist ni Englewood. Nigba ti jennifer pè ọmọ ọdun meje ni ó bẹrẹ sini kọrin pẹlu atilẹyin Iya Iya rẹ agba Julia[2]. Ni Óṣu January ọdun 2002, Óṣèrè lóbinrin naa sign recording contract rẹ̀ akọkọ pẹlù Record Righteous.
Ni ọdun 1999, Hudson fẹ James Payton ni ọmọ ọdun meji dinlóógun. Awọn mejeji pinya ni ọdun 2007. Ni ọdun 2008, óṣèrè lóbinrin naa fẹ David Otunga to si bi ọmọ ọkunrin David Daniel Otunga. Awọn mèjèji pinya ni ọdun 2017[3][4].
Ẹkọ
àtúnṣeJennifer kẹkọ ni Dunbar Vocational High School nibi to ti jade ni ọdun 1999 lẹyin rẹ ni óṣèrè lóbinrin naa lọsi ilè iwè giga Langston ṣugbọn ti o kurò nigba ọkan rẹ fasi ilé nibi o lọsi collegi Kennedy-King[5].
Ami Ẹyẹ ati Idanilọla
àtúnṣeHudson jẹ óbinrin to kèrè ju ilẹ Africa-America keji lati gba Ami ẹyẹ entertainment America mẹrin to pataki EGOT (Ami ẹyẹ ti Emmy, Grammy, Oscar ati Tony)[6][7][8]. Óṣèrè lobinrin naa gba irawọ lori Hollywood Walk of Fame ni ọdun 2013[9][10].
Itokasi
àtúnṣe- ↑ https://time.com/6213692/jennifer-hudson-karamo-brown-talk-show-future/
- ↑ https://www.allmovie.com/artist/jennifer-hudson-p454405
- ↑ https://web.archive.org/web/20111002133458/http://blog.zap2it.com/pop2it/2008/09/is-jennifer-hud.html
- ↑ https://www.wwe.com/superstars/david-otunga
- ↑ https://www.nwitimes.com/news/state-and-regional/true-crime-academy-award-winner-jennifer-hudson-was-cinderella-until-she-wasn-t/article_1022360c-c8ad-5589-9284-28d130de6a47.html
- ↑ https://www.hollywoodreporter.com/lifestyle/arts/jennifer-hudson-tony-nomination-egot-strange-loop-1235143263/
- ↑ https://www.latimes.com/entertainment-arts/story/2022-06-12/jennifer-hudson-egot-winner
- ↑ https://variety.com/2022/tv/news/jennifer-hudson-egot-tony-a-strange-loop-1235292057/
- ↑ https://walkoffame.com/jennifer-hudson/
- ↑ http://blackyouthproject.com/jennifer-hudson-receives-star-on-hollywood-walk-of-fame/