Jimoh Aliu
Jímọ̀ Àlíù, MFR (November 11, 1939 – September 17, 2020), tí a tún mọ̀ sí Àwòrò, jẹ́ agbẹ́gilére òṣèré orí-ìtàgé ati sinimá, olùkọ̀tàn àti adarí eré ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. [1]
Jímọ̀ Àlíù | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Òké-Ìmẹ̀sí, Nigeria | 11 Oṣù Kọkànlá 1939
Aláìsí | 17 September 2020 Adó Èkìtì, Nàìjíríà | (ọmọ ọdún 80)
Orílẹ̀-èdè | Nàìjíríà |
Orúkọ míràn | Àwòrò |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Nàìjíríà |
Iṣẹ́ |
|
Ìgbà iṣẹ́ | 1959–2020 |
Ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀
àtúnṣeWọ́n bí alàgbà Jímọ̀ ní ọjọ́ kọkànlá oṣù Kọkànlá ọdún 1939 ní Ìlú Òké-Ìmẹ̀sí ní Ìpínlẹ̀ Èkìtì ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Bàbá rẹ̀ Àlíù Fákọ̀yà, jẹ́ baba aláwo tí ó jẹ́ ọmọ bíbí Ìlú Òké-Ìmẹ̀sí, nígbà tí ìyá rẹ̀ jẹ́ ọmọ bíbí Ìlú Ìlórò-Èkìtì.[2][3]
Ìṣe rẹ̀.gẹ́gẹ́ bí òṣèré
àtúnṣeÀlíù dara pọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ òṣèré Akin Ògúngbè nígbà tí gbajú-gbajà òṣèré yí gbé eré ìtagé kan wá sí ìlú rẹ̀.[4] Ní ọdún 1966, ó dá ẹgbẹ́ òṣèré tirẹ̀ ìyẹn "Jímọ̀ Àlíù Concert Party" tí gbé kalẹ̀ ní ílú Ìkàrẹ́ ní Ìpínlẹ̀ Òndó lẹ́yìn tí ó ti lo ọdún méje lẹ́yìn nínú ẹgbẹ́ Ògúngbè[5]
Àwòrò dara pọ̀ mọ́ ilé iṣẹ́ Ológun ilẹ̀ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ní ọdún 1967 àmọ́ ó fẹ̀yìn tì ní ọdún 1975 kí ó lè fọkàn balẹ̀ láti ṣe iṣẹ́ eré orí-ìtàgé, àti láti mú ìdàgbà-sókè bá eré lábẹ́ orúkọ ilé iṣẹ́ ìgbéréjáde rẹ̀ tí ó pè ní Jímọ̀ Àlíù Cultural Group[6] Jímọ̀ ti gbé àwọn eré oríṣiríṣi Yánpọn-yánrin, Ikú Jàre Ẹ̀dá, Fọ́pomọ́yọ̀ jáde lórí ẹ̀rọ amóhù-máwòrán.[7][8]
Ikú rẹ̀
àtúnṣeJímọ̀ Àlíù kú ní ọmọ ọgọ́rin ọdún ní ọjọ́ kẹtàdínlógún oṣù kẹsàán ọdún 2020 sí ilé-ẹ̀kọ́ ìkọ́ṣẹ́ ìṣègùn ti Fásitì Adó-Èkìtì lẹ́yìn àìsàn ránpẹ́. .[9]
Àwọn sinimá àgbéléwò rẹ̀
àtúnṣe- Fọ́pomọ́yọ̀
- Yánpọn-yánrin
- Àjálù
- Àrélù
- Igbó Ẹlẹ́jẹ̀
- Ìrìnkèrindò
- Rúkèrúdò
Àwọn àmì ẹ̀yẹ rẹ̀
àtúnṣeÀwọn ìtọ́ka sí
àtúnṣe- ↑ "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2015-02-16. Retrieved 2020-09-18.
- ↑ Administrator. "MY DIVORCE WITH ORISABUNMI WAS DESTINED----Chief Jimoh Aliu a.k.a. Aworo MFR — nigeriafilms.com". nigeriafilms.com. Retrieved 16 February 2015.
- ↑ "From stage to traditional medicine". The Punch — Nigeria's Most Widely Read Newspaper. Archived from the original on 16 February 2015. Retrieved 16 February 2015. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Veteran actor, Ogungbe, dies at 78". The Punch — Nigeria's Most Widely Read Newspaper. Archived from the original on 16 February 2015. Retrieved 16 February 2015. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "For Ogungbe, dramatists besiege Abeokuta". The Punch — Nigeria's Most Widely Read Newspaper. Archived from the original on 16 February 2015. Retrieved 16 February 2015. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Strangers to their mother tongues: Home-bred Nigerians who don’t speak their native languages". The Punch — Nigeria's Most Widely Read Newspaper. Archived from the original on 16 February 2015. Retrieved 16 February 2015. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "African Cinema". google.nl. Retrieved 16 February 2015.
- ↑ BOLDWIN ANUGWARA. "How I lied to become music star – KSA". Newswatch Times. Archived from the original on 16 February 2015. Retrieved 16 February 2015. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ BREAKING: Veteran Yoruba Actor, Jimoh Aliu, Is Dead, To Be Buried On Friday