João Lourenço
João Manuel Gonçalves Lourenço, GColIH (pípè:Jao Manuel Gonsafes Lourenso ọjọ́ìbí 5 March 1954) ni olóṣèlú ará Angola tó ti wà nípò bíi Ààrẹ ilẹ̀ Àngólà láti 26 September 2017.[2] Tẹ́lẹ̀tẹ́lẹ̀, ó jẹ́ Alákóso Ètò Àbò ilẹ̀ Àngólà láti 2014 dé 2017. Ní September 2018 ó di Alága ẹgbẹ́ olóṣèlú People's Movement for the Liberation of Angola (MPLA), tíí ṣe ẹgbẹ́ olóṣèlú tó wà lórí ìjọba.
João Lourenço | |
---|---|
Lourenço in 2018 | |
4th President of Angola | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 26 September 2017 | |
Vice President | Bornito de Sousa |
Asíwájú | José Eduardo dos Santos |
Minister of National Defense | |
In office 22 April 2014 – 26 September 2017 | |
Ààrẹ | José Eduardo dos Santos |
Asíwájú | Cândido Pereira dos Santos Van-Dúnem |
Arọ́pò | Salviano de Jesus Sequeira |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 5 Oṣù Kẹta 1954 Lobito, Portuguese Angola (now Angola) |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | MPLA (1974–present) |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Ana Afonso Dias |
Àwọn ọmọ | 6 |
Alma mater | Industrial Institute of Luanda Lenin Superior Academy |
Nickname(s) | JLo[1] |
Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Joao Lourenco: Can 'Angola's JLo' fill Dos Santos' shoes?". BBC News. https://www.bbc.com/news/world-africa-41037721. Retrieved 25 August 2017.
- ↑ Eisenhammer, Stephen (September 26, 2017). "Angola's first new president in 38 years vows to fight graft". Reuters. https://www.reuters.com/article/us-angola-politics/angolas-first-new-president-in-38-years-vows-to-fight-graft-idUSKCN1C12G0?il=0. Retrieved 27 September 2017.