Ààrẹ ilẹ̀ Àngólà
(Àtúnjúwe láti President of Angola)
Ààrẹ ilẹ̀ Àngólà (Pọrtugí: Presidente de Angola) ni olórí orílẹ̀-èdè àti olórí ìjọba ní orílẹ̀-èdè Àngólà. Gẹ́gẹ́ bí òfin-ìbágbépọ̀ tí wọ́n gbàtọ́ ní ọdún 2010 ṣe sọ, ipò alákóso àgbà jẹ́ píparẹ́; agbára aláṣẹ bọ́ sí ọwọ́ áárẹ.
Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Àngólà President of the Republic of Angola | |
---|---|
Iye ìgbà | 5 years, renewable once |
Ẹni àkọ́kọ́ | Agostinho Neto |
Formation | 11 November 1975 |
Deputy | Vice President of Angola |
Owó osù | 1,024,207.74 Kwanzas annually[1] |
Ìgbà ẹ̀mejì fún ọdún márùún ní ààrẹ le fi wà ní ipò.
Ní Osù Kínní ọdún 2010 ni Iléìgbìmọ̀ Aṣòfin fọwọ́sí òfin-ìbágbépọ̀ tuntun, lábẹ́ òfin yìí, olórí ẹgbẹ́ ọ̀ṣèlú tó ní iye ìjókòó tó pọ̀ jùlọ ní iléaṣòfin ni yíò di ààrẹ, kò ní jẹ́ dídìbòyàn tààrà látọwọ́ àwọn aráàlú.[2]
João Lourenço ni Ààrẹ ilẹ̀ Àngólà lọ́wọ́lọ́wọ́, ó bọ́ sí orí ipò ní 26 September 2017.
Àtòjọ àwọn ààrẹ ilẹ̀ Àngólà (1975–d'òní)
àtúnṣeẸ tún wo
àtúnṣe
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Manje, Bernardino. "Estado reajusta salários - Política - Jornal de Angola - Online". jornaldeangola.sapo.ao. Archived from the original on 2020-03-03. Retrieved 2020-06-23.
- ↑ Angola abolishes presidential polls in new constitution BBC News, 21 January 2010