Jumoke Akindele
Jumoke Akindele jẹ́ agbẹjọ́rò ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó sì tún jẹ́ obìnrin Olórí àkọ́kọ́ ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin ìpínlẹ̀ Ondo.[2][3][4]
Jumoke Akindele | |
---|---|
In office 27 May 2014 – 20 March 2017(kòwẹ́ fipòsílẹ̀)[1] | |
Constituency | Òndó, Okitipupa Constituency II |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Òndó, Nàìjíríà |
Ọmọorílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | People's Democratic Party |
Residence | Okitipupa |
Occupation | Agbẹjọ́rò |
Ìgbà èwe àti bí ó ṣe kẹ́kọ̀ọ́
àtúnṣeJumoke Akindele ni wọ́n bí ni Okitipupa, ilu kan ni Ipinle Ondo ni guusu ìwò òòrùn Nàìjíríà. O lọ íle ẹ̀kọ́ alakobere re ni St John's Primary School ni Okitipupa ki o to lo si St Louis Girls Secondary School, Ondo nibi ti o ti gba Iwe eri Ile-iwe West Africa(WAEC) ni odun 1981. Jumoke gba oye ẹyẹ ninu imo ofin lati Yunifásítì Ọbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀, Ilé-Ifẹ̀ o si se ise asofin fun opolopo odun ki o to di oselu lodun 2006.
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Olowookere, Dipo (March 20, 2017). "Jumoke Akindele Resigns as Ondo Speaker - Business Post Nigeria". Business Post Nigeria. Retrieved May 22, 2022.
- ↑ "Ondo State House of Assembly Speaker, Mrs. Jumoke Akindele resigns". TVC News. March 21, 2017. Retrieved May 22, 2022.
- ↑ "Why women are lagging behind in politics- Ondo Speaker". The Nation Newspaper. June 8, 2014. Retrieved May 22, 2022.
- ↑ Yakubu, Temitope (July 28, 2019). "Ondo ex-speaker: Akeredolu treating state lawmakers like errand boys". TheCable. Retrieved May 22, 2022.