Jumoke Verissimo (tí wọ́n bí ní 26 December 1979 ní Èkó) jẹ́ òǹkọ̀wé ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, akéwì, òǹkọ̀wé ìtàn àròsọ, òǹkọ̀wé ìtàn ọmọdé àti alárìíwísí.

Jumoke Verissimo
Ọjọ́ìbí26 Oṣù Kejìlá 1979 (1979-12-26) (ọmọ ọdún 45)
Lagos, Lagos Island, Nigeria
Orílẹ̀-èdèNigerian
Ẹ̀kọ́University of Alberta (PhD)University of Ibadan (MA), Lagos State University (BA)
Iṣẹ́Poet. Novelist. Academic.
Gbajúmọ̀ fúnWriting A Small Silence, I am memory

Ayé rẹ̀

àtúnṣe

Wọ́n bí Jumoke sí Èkó . Ó kẹ́kọ̀ọ́ gboyè master's ní African studies (performance) láti University of Ibadan àti bachelor's degree nínú ẹ̀kọ́ English literature láti Lagos State University. Ó ti ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bíi olóòtú, olóòtú àgbà, copywriter àti akọ̀ròyìn fún àwọn ìwé-ìròyìn bíi The Guardian àti NEXT. Lọ́wọ́lọ́wọ́ báyìí, Jumoke ń gbé ní Canada pẹ̀lú ọmọbìnrin rẹ̀, ó sì ń ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bíi aṣèránwọ́ ọ̀jọ̀gbọ́n ní Toronto Metropolitan University .[1]

Iṣẹ́ rẹ̀

àtúnṣe

Peoples Daily[2] ṣe àpèjúwe iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bíi "èyí tó dúró fún ẹ̀dùn ọkàn àti ìmọ̀lára, tó sí jẹ́ àkéjáde ẹkún àwùjọ." The Punch náà ṣe àpèjúwe rẹ̀ bíi, "ọ̀kan lára àwọn tó máa yí ojú ìwò lítíréṣọ̀ Nàìjíríà padà", lẹ́yìn ìwé rẹ̀ àkọ́kọ́, èyí tí àwọn ènìyàn gbà tọwọ́ tẹsẹ̀ káàkiri orílẹ̀-èdè. Wọ́n ṣàfihàn iṣẹ́ rẹ̀ ní Migrations (Afro-Italian), Wole Soyinka ed., Voldposten 2010 (Norway), Livre d'or de Struga (Poetes du monde, sous le patronage de l'UNESCO) àti àwọn àkọsílẹ̀ loríṣiríṣi. Díẹ̀ lára àwọn ewì rẹ̀ ni wọ́n ti tú sí èdè Italian, Norwegian, French, Japanese, Chinese, àti Macedonian.[citation needed] Ìwé ìtàn àròsọ Veissimo ti ọdún 2019, A Small Silence (Cassava Republic) ni wọ́n yàn gẹ́gẹ́ bíi èyí tó jáwé olúborí ti ẹ̀bùn Aidoo-Snyder fún iṣẹ́ tó dára jù lọ.[3]

Àwọn àmì-ẹ̀yẹ rẹ̀

àtúnṣe

Ìtàn àròsọ

àtúnṣe
  • I Am Memory DADA Books, Lagos, 2008 ISBN No: 978-978-088-065-1
  • The Birth of Illusion FULLPOINT, Nigeria, 2015 ISBN No: 978-978-946-697-9

Iṣẹ́ àtúnṣe

àtúnṣe

Ìwé àwọn ọmọdé

àtúnṣe

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Jumoke Verissimo on ResearchGate". ResearchGate. Retrieved 17 April 2019. 
  2. "Interview on People's Daily Newspaper, Nigeria". Archived from the original on 8 July 2013. Retrieved 7 July 2013.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  3. News, BrittlePaper (25 November 2020). "Jumoke Verissimo Wins the Aidoo-Snyder Prize for Best Creative Work". BrittlePaper. https://brittlepaper.com/2020/11/jumoke-verissimo-wins-the-aidoo-snyder-prize-for-best-creative-work/. Retrieved 2 May 2021. 
  4. 4.0 4.1 "Obiwu: AWF 2009 LITERARY CONTEST SHORT LIST". Archived from the original on 20 July 2019. Retrieved 2 November 2021.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  5. "Shortlist for £10,000 Ondaatje Prize announced". Books+Publishing (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-04-21. Retrieved 2020-05-07. 
  6. "Aidoo-Snyder Book Prize". 2020-10-21. Retrieved 2021-05-02.