Kókó ọmú
Kókó omú tí àwon míràn mòn sí orí omú jé ará omú tí o dide sita tí omi omú sì n gbà jáde. [1] Kókó omú àti agbegbe rè(areola) ma n dúdú ju ara omú to ku lo, bí o tile jé wipe didudu kókó omú lè jé tori oyún(àwon oloye gbagbo pé ìdí èyi nipé kí omo ba le tete rí orí omú nígbà tí o ba fé jeun [2] ), àkókò nkan osu tàbí tori aìsàn. [3] Kókó omú le dide sókè si nígbà otutu tàbí nígbà tí nkan bà kan, o lè jé enu omode nígbà tí fun lomu tàbí iwofokan nigba ibalopo, aìsàn náà tún le fa kí ori omú le [4]
Àwon Ìtókasí
àtúnṣe- ↑ "Definition of NIPPLE". Merriam-Webster. 2022-03-01. Retrieved 2022-03-06.
- ↑ "The Areola and Breastfeeding Concerns, What to Look For". Verywell Family. 2015-03-09. Archived from the original on 2022-03-06. Retrieved 2022-03-06.
- ↑ Downey, Andrea (2018-04-04). "The 7 things that make your nipples DARKER - and when it could be a deadly sign". The Sun. Retrieved 2022-03-06.
- ↑ Scaccia, Annamarya (2017-08-29). "Why Are My Nipples Hard? 10 Possible Causes". Healthline. Retrieved 2022-03-06.