Kamalesh Sharma

Olóṣèlú Ọmọ Orílẹ̀-èdè Indian

Kamalesh Sharma (ojoibi 30 September 1941)[1] ni Akowe Agba egbe Ajoni awon Orile-ede lowolowo lati 2008, leyin igba to ti je teletele Asakoso Agba fun India ni ilu London.[2]

Kamalesh Sharma
Secretary General of the Commonwealth of Nations
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
April 1 2008
AsíwájúDon McKinnon
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí30 Oṣù Kẹ̀sán 1941 (1941-09-30) (ọmọ ọdún 83)
Índíà India

Kamalesh Sharma pari ile-eko Modern School, Barakhamba Road, New Delhi, St. Stephen's College ni Delhi ati King's College, Cambridge.[3] Sharma je osise ni Ile-ise Oro Okere India lati 1965 de 2001. O di Asoju Patapata India si United Nations ki o to feyinti. Lati 2002 de 2004, o di asoju pataki Akowe Agba U.N. si East Timor. O je yiyan gege bi Asakoso Agba fun India si Britani ni 2004. Ohun ni Igbakeji-Aare Royal Commonwealth Society. Ohun tun ni Chancellor fun Queen's University Belfast (from July 2009)[4][5]