Kamuku National Park jẹ́ ọ̀kan lára àwọn pápá ìṣeré Nàìjíríà tí ó wà ní Ìpínlẹ̀ Kàdúná, Nàìjíríà, pẹ̀lú ilẹ̀ tí ó tó a 1,120 km2.

Nítorí àìsí àbò tí kò péye ní agbègbè náà, àjọ pápá ìṣeré fún orílẹ̀ èdè Nàìjíríà dáwọ́ iṣẹ́ dúró ní pápá ìṣeré náà, àti ní pápá ìṣeré Kainji National Park àti Chad Basin National Park.[1]

Ìtàn àti ibi tí ó wà àtúnṣe

Pápá ìṣeré náà wà ní ìwọ̀ oòrùn Ìpínlẹ̀ Kaduna, ó sì wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ Kwiambana Game Reserve.[2] Àjọ Native Authority Forest Reserve of Birnin Gwari ni ó da kalẹ̀ ní oin 1936 lábé ìjọba àríwá orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.[3]

Àwọn Ìtọ́kasí àtúnṣe

  1. Adanikin, Olugbenga. "Kainji National Park, two others suspend operations over insecurity". International Centre for Investigative Reporting. Retrieved 27 October 2021. 
  2. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named calabash
  3. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named NNPS