Lola Margaret
Lola Margaret tí orúkọ àbísọ rẹ̀ gan-an ń jẹ́ Lola Margaret Oladipupo jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèrébìnrin, olùdarí àti olóòtú sinimá àgbéléwò ọmọ Nàìjíríà. Ó di gbajúmọ̀ lẹ́yìn tí ó kópa olú-ẹ̀dá-ìtàn nínú eré tí àkọlé rẹ̀ ń jẹ́ Bísọ́lá Aláàánú.[1]
Lola Margaret | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Lola Margaret Oladipupo Iléṣà, Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun |
Orílẹ̀-èdè | Nàìjíríà |
Iṣẹ́ |
|
Ìgbà iṣẹ́ | Ọdún 2008 títí di àsìkò yìí |
Ìgbà èwe àti ìkẹ́kọ̀ọ́
àtúnṣeWọ́n bí Lọlá ní Iléṣà, ní a city located in Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Ibẹ̀ ló ti kàwé àkọ̀bẹ̀rẹ̀ àti girama. Ó kàwé gbàwé ẹ̀rí dìgírì nínú ìmọ̀ ẹ̀kọ́ ìtàn àti ìbáṣepọ̀ orílẹ̀-èdè sí orílẹ̀-èdè, (History and International Relations) ní Yunifásítì Ìpínlẹ̀ Èkó, Lagos State University.[2]
Iṣẹ́ rẹ̀
àtúnṣeLọlá Margaret bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ tíátà pẹ̀lú ìràlọ́wọ́ Bolaji Amusan, gbajúmọ̀ òṣèré aláwàdà ọmọ Nàìjíríà.[3] Ó di gbajúmọ̀ lẹ́yìn tí ó kópa olú-ẹ̀dá-ìtàn nínú eré tí àkọlé rẹ̀ ń jẹ́ Bísọ́lá Aláàánú. Lolá tí kópa nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ sinimá mìíràn bíi Ẹyin Akùkọ àti Ọmọ Ọlọ́rọ̀, èyí tí òun náà ṣe olóòtú rẹ̀ tí àwọn àgbà òṣèré bíi Faithia Balogun àti Mercy Aigbe kópa nínú rẹ̀. [4]. Lẹ́yìn èyí, ó ti kópa nínú oríṣiríṣi sinimá àgbéléwò.
Àtòjọ àṣàyàn àwọn sini á àgbéléwò rẹ̀
àtúnṣeÀwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Ben-Nwankwo, Nonye (28 January 2012). "The last thing I’d do is marry a politician – Lola Margaret". The Punch. Archived from the original on 24 September 2015. https://web.archive.org/web/20150924120513/http://www.punchng.com/feature/encounter/the-last-thing-id-do-is-marry-a-politician-lola-margaret/. Retrieved August 24, 2015.
- ↑ "Yoruba Actress, Lola Margaret Says She’s Not Pregnant". Information Nigeria. October 3, 2012. http://www.informationng.com/2012/10/yoruba-actress-lola-margaret-says-shes-not-pregnant.html. Retrieved August 24, 2015.
- ↑ "I can't marry an actor —Lola Margaret". The Nation. 5 February 2012. http://www.thenationonlineng.net/2011/index.php/index.php%3Fnews%3D43194%26output_type%3Drss&sa=U&ved=0CBYQFjAGahUKEwiy8f3czMLHAhVCshQKHYynCPc&usg=AFQjCNGjOwkESmtu-FwJW_flhFStmc--rA. Retrieved 24 August 2015.
- ↑ Odunowo, Bunmi (10 February 2012). "Yoruba Actress, Lola Margaret Premieres ‘Omo". Archived from the original on 6 March 2016. https://web.archive.org/web/20160306152554/http://bunmiodunowo.com/yoruba-actress-lola-margaret-premieres-omo-oloro-in-london/. Retrieved 24 August 2015.
- ↑ "Eyin akuko (2008)" at IMDb.
- ↑ "OMO OLORO...", YouTube.
- ↑ "The Power of Love (Agbara Ife) – Laide Bakare, Bigvai Jokotoye Storm Lola Margaret Movie Premiere" Archived 2020-10-12 at the Wayback Machine., Slickson Post, 8 May 2016.