Logan February
Logan February tí wọ́n bí ní ọdún 1999 jẹ́ akéwì, alágbéyẹ̀wò orin, alápilẹ̀kọ, akọrin, olórin ati ajìjàngbara fún àwọn LGBTQ.
Logan February | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Àsìṣe ìgbéọ̀rọ̀sílẹ̀: Àìdámọ̀ àmì ìdádúró-ọ̀rọ̀ sókí "{". 23 April 1999 ìpínlẹ̀ Anambra |
Orílẹ̀-èdè | Nàìjíríà |
Iléẹ̀kọ́ gíga | University of Ibadan |
Iṣẹ́ | Poet, LGBTQ activist, singer, songwriter, music reviewer |
Ìgbà iṣẹ́ | 2016–present |
Gbajúmọ̀ fún | Poerty, LGBTQ Activism, and Music review |
Notable work | In the Nude, 2019. |
Website | loganfebruary.com |
Ibẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀
àtúnṣeWọ́n bí Logan February ní Ìpínlẹ̀ Anámbra ní ọjọ́ kẹ̀tàlélógún oṣù kẹrin ọdún 1999, ó sì dàgbà sí ìlú Ìbàdàn. Ó kẹ́kọ́ nípa psychology ní ilé-ẹ̀kọ́ Yunifásítì ìlú Ìbàdàn.[1][2][3][4][5][6]
Iṣẹ́ rẹ̀
àtúnṣeÒun ni ònkọ́wé In the Nude, tí wọ́n gbé jáde ní ọdún 2019 lábẹ́ ilé-iṣẹ́ Ouida Poetry àti Mannequin in the Nude tí wọ́n gbé jáde ní abẹ́ ilé iṣẹ́ ìtẹ̀wé PANK Books ní orílẹ̀-èdè in Amẹ́ríkà.[7] Òun àti ẹnìkan ni wọ́n pawọ́ pọ̀ kọ ìwé tí wọ́n pe ní Painted Blue with Saltwater ní ọdún 2018.[8] wọ́n sì kọ How to Cook a Ghost ní ọdún 2017 tí wọ́n gbé jáde lábẹ́ ilé-iṣẹ́ ìtẹ̀wé Glass Poetry Press.[9] Logan jẹ́ ọ̀kan lára àwọn tí wọ́n yàn fún amì-ẹ̀yẹ Pushcart fún àkójọ iṣẹ́ wọn bíi Mannequin in the Nude níbi ìdíj African Poetry Book Fund. Wọ́n sì tún yàn án fún àmì-ẹ̀yẹ Brittle Paper.[10][11][12]
Gẹ́gẹ́ bí ajìjàngbara fún LGBTQ ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, òun ni alápilẹ̀kọ fún "There Is Hope" lásìkò ìpàdé Pride month ní ọdún 2020 fún búlọ́gì Ynaija[13]
Àwọn ìwé rẹ̀
àtúnṣe- How to Cook a Ghost (2017)
- Painted Blue with Saltwater (2018)
- In the Nude (2019)
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Painted Blue With Saltwater by Logan February". Indolent Books. 28 February 2018. Retrieved 2020-07-24.
- ↑ Bivan, Nathaniel (11 January 2020). "The Last Good Book I Read...". Daily Trust. Archived from the original on 2020-07-24. Retrieved 2020-07-24.
- ↑ Mordi, Melissa (13 May 2019). "Logan February: Poet "In Glorious Bloom"". The Guardian Nigeria. Archived from the original on 2020-11-28. https://web.archive.org/web/20201128190253/https://guardian.ng/life/logan-february-poet-in-glorious-bloom/. Retrieved 2020-07-24.
- ↑ Gänsler, Katrin (27 October 2019). "Literaturfestival in Lagos: Rückbesinnung auf Herkunft und Identität" (in de-DE). Deutsche Welle. https://www.dw.com/de/literaturfestival-in-lagos-r%C3%BCckbesinnung-auf-herkunft-und-identit%C3%A4t/a-51008430. Retrieved 2020-07-24.
- ↑ "Bio". Logan February (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-11-19. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ February, Logan. "Original Logi Bear (@LoganFebruary)". Twitter (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-11-19. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ February, Logan (15 March 2019). Mannequin in the nude (First ed.). USA: Pank Books. ISBN 978-1948587075. https://books.google.com/books?id=tPSwvgEACAAJ. Retrieved 2020-07-24.
- ↑ February, Logan (15 December 2017). Painted blue with saltwater. USA: Indolent Books. ISBN 9781945023088. https://books.google.com/books?id=-ro3swEACAAJ. Retrieved 2020-07-24.
- ↑ February, Logan (15 August 2017). Frame, Anthony. ed. How to cook a ghost. USA: Glass Poetry Press. ISBN 978-0997580532. https://www.google.com.ng/search?tbo=p&tbm=bks&q=bibliogroup:%22Glass+chapbook+series%22&source=gbs_metadata_r&cad=3. Retrieved 2020-07-24.
- ↑ "The Top 15 Debut Books of 2019". Brittle Paper. 29 January 2020. https://brittlepaper.com/2020/01/the-top-15-debut-books-of-2019/. Retrieved 2020-07-24.
- ↑ "Logan February". Global Poetics Project. Global Poetics. 11 July 2019. Archived from the original on 2020-07-24. Retrieved 2020-07-24.
- ↑ "Tjawangwa (TJ) Dema Named Winner of 2018 Sillerman First Book Prize for African Poets". African Poetry Book Fund.
- ↑ "#YNaijaNonBinary: 'There is Hope', A Note from the Guest Editor, Logan February". World News. 2020-06-05. https://theworldnews.net/ng-news/ynaijanonbinary-there-is-hope-a-note-from-the-guest-editor-logan-february. Retrieved 2020-07-27.