Músílíù Ìṣọ̀lá
'Músílíù Hárúnà-Ìṣọ̀lá jẹ́ gbajúmọ̀ olórin Àpàlà. Ó jẹ́ ọmọ bíbí Akọrin Àpàlà tí ó ti di olóògbé, Hárúnà Ìṣọ̀lá. Gbajúmọ̀ rẹ̀ gbòde kan nígbà tí ó ṣe àtúnkọ orin bàbá rẹ̀ kan tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ "Sóyòyò" lọ́dún 2004.[1]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Musiliu Haruna Ishola & His Apala Remix - Soyoyo". Awesome Tapes From Africa. 2016-12-30. Retrieved 2019-12-30.