Mọ́tò
Àyọkà yìí jẹ mọ́ nípa the means of transportation . Fún ìtumọ́ míràn, ẹ wo: Mọ́tò (ìṣojútùú).
Ọkọ̀ tàbí Mọ́tò (ni ó wá láti inú èdè Látìnì: vehiculum[1]) ni ó jẹ́ ẹ̀rọ tí ó ń gbé ènìyàn tàbí ẹrù láti ibìkan sí ibòmíràn. Ọkọ̀ lè jẹ́ kẹ̀kẹ́ Alùpùpù, kẹ̀kẹ́, ọkọ̀ àjàgbé, Rélùwéè, ọkọ̀ ojú-omi, ọkọ̀ akérò, ọkọ̀ akérò ojú-omi, ọkọ̀ òfurufú , bàlúù ati bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.[2] Àwọn ọkọ̀ arinlẹ̀ ni a pín sí Àwọn ọkọ̀ tí wọ́n ń lo ipá tí s mọ̀ sí (force) láti fi lè kúrò ní ojú kan sí òmíràn Webstore.anis.org</ref>
Àwọn itọ́ka sí
àtúnṣe- ↑ "vehicle, n.", OED Online, Oxford University Press, November 2010
- ↑ Halsey, William D. (Editorial Director): MacMillan Contemporary Dictionary, page 1106. MacMillan Publishing, 1979. ISBN 0-02-080780-5