Maria Hajara Braimoh (tí a bí ní ọjọ́ kọkàndínlógún, oṣù kìíní, ọdún 1990) jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Naijiria tó ń gbá Badminton.[1] Ó wà lára àwọn ẹgbẹ́ ti Nàìjíríà tó gbá Badminton ní ọdún 2007 àti ìdíje gbogboogbò ti ilẹ̀ Afrika ní ọdún 2011. Braimoh tún kópa nínú ìdíje ti Commonwealth tí wọ́n ṣe ní odún 2010, ní New Delhi, India.[2]

Àwọn àṣeyọrí rẹ̀

àtúnṣe

Ìdíje gbogboogbò ti ilẹ̀ Afrika

àtúnṣe

Àwọn obìnrin nìkan

Year Venue Opponent Score Result
2011 Escola Josina Machel, Maputo, Mozambique   Susan Ideh 12–21, 21–19, 7–21   Bronze

Àdàpọ̀ àwọn obìnrin

Year Venue Partner Opponent Score Result
2015 Gymnase Étienne Mongha,

Brazzaville, Republic of the Congo

  Grace Gabriel   Juliette Ah-Wan

  Allisen Camille

13–21, 16–21   Bronze

Àwọn olúborí ilẹ̀ African

àtúnṣe

Àwọn obìnrin nìkan

Year Venue Opponent Score Result
2010 Kampala, Uganda   Stacey Doubell 18–21, 17–21   Bronze

Àdàpọ̀ àwọn obìnrin

Year Venue Partner Opponent Score Result
2011 Marrakesh, Morocco   Susan Ideh   Annari Viljoen

  Michelle Edwards

9–21, 16–21   Silver
2010 Kampala, Uganda   Susan Ideh   Annari Viljoen

  Michelle Edwards

6–21, 6–21   Silver

Ìdíje gbogboogbò ti BWF

àtúnṣe

Àdàpọ̀ àwọn obìnrin

Year Tournament Partner Opponent Score Result
2015 Nigeria International   Grace Gabriel   Cemre Fere

  Ebru Yazgan

14–21, 14–21 Runner-up
2014 Laagos International   Dorcas Ajoke Adesokan   Tosin Damilola Atolagbe

  Fatima Azeez

21–19, 22–20 Winner
2010 Kenya International   Susan Ideh   Annari Viljoen

  Michelle Edwards

10–21, 21–12, 10–21 Runner-up

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Players: Braimoh Maria". bwfbadminton.com. Badminton World Federation. Retrieved 2 December 2016. 
  2. "Braimah Maria Hajara". cwgdelhi2010.infostradasports.com. New Delhi 2010. Archived from the original on 2 December 2016. Retrieved 2 December 2016.