Fatima Azeez
Titilayo Fatima Azeez (tí a bí ní ọjọ́ kọkànlelógún, osú kejìlá, ọdún 1992) jẹ́ agbá bọ́ọ̀lù badminton ti orílè-èdè Naijiria.[1] Ní ọdún 2010, ó parí Summer Youth Olympics ní Singapore.[2] Ní ọdún 2011, ó jẹ èbùn ti All-Africa Games ní Maputo, Mozambique.[3]
Àwọn àṣeyọrí rẹ̀
àtúnṣeAll-Africa Games
àtúnṣeÌdíje àwọn obìnrin méjì
Year | Venue | Partner | Opponent | Score | Result |
---|---|---|---|---|---|
2011 | Escola Josina Machel, | Grace Daniel | Camille Allisen | 22–24, 15–21 | Bronze |
Ìdíje ti ilẹ̀ Africa
àtúnṣeObìnrin ọ̀wọ́ kan nìkan
Year | Venue | Opponent | Score | Result |
---|---|---|---|---|
2012 | Arat Kilo Hall, Addis Ababa, Ethiopia | Grace Gabriel Ofodile | 19–21, 21–14, 16–21 | Silver |
Obìnrin ọ̀wọ́ méjì
Year | Venue | Partner | Opponent | Score | Result |
---|---|---|---|---|---|
2014 | Lobatse Stadium, | Tosin Damilola Atolagbe | Kate Foo Kune | 16–21, 23–21, 17–21 | Bronze |
Ìdíje àgbáyé ti BWF
àtúnṣeObìnrin ọ̀wọ́ kan nìkan
Year | Tournament | Opponent | Score | Result |
---|---|---|---|---|
2013 | Nigeria International | Tosin Damilola Atolagbe | 21–16, 15–21, 22–20 | Winner |
Women's doubles
Year | Tournament | Partner | Opponent | Score | Result |
---|---|---|---|---|---|
2014 | Nigeria International | Tosin Atolagbe |
Shamim Bangi Hadia Hosny
|
5–11, 10–11, 10–11 | Runner-up |
2014 | Lagos International | Tosin Atolagbe | Dorcas Adesokan | 19–21, 20–22 | Runner-up |
2014 | Uganda International | Tosin Atolagbe | Dorcas Adesokan | 14–21, 21–9, 21–12 | Winner |
2013 | Nigeria International | Tosin Atolagbe | Augustina Sunday | 18–21, 13–21 | Runner-up |
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Players: Fatima Azeez". Badminton World Federation. Retrieved 2 December 2016.
- ↑ "Youth Olympics – The Best of the Rest?". Badzine.net. http://www.badzine.net/2010/08/youth-olympics-the-best-of-the-rest/. Retrieved 16 January 2018.
- ↑ "Diários dos X Jogos Africanos: África do Sul e Nigéria repartem Ouro do Badminton" (in pt). @Verdade. Archived from the original on 4 July 2018. https://web.archive.org/web/20180704213617/http://pda.verdade.co.mz/jogos-africanos/22125-diarios-dos-x-jogos-africanos-africa-do-sul-e-nigeria-repartem-ouro-do-badminton. Retrieved 16 January 2018.