Maureen Ihua jẹ́ òṣèrébìnrin ilẹ̀ Nàìjíríà tó ti kópa nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ fíìmù bíi Domitila, Unplanned and Unpredictable. Ó ṣe fíìmù pẹ̀lú Liz Benson àti Regina Askia.

Maureen Ihua
Bibi
Ipinle Rivers
Omo ilu Nigeria
Iṣẹ iṣe Oṣere
Awọn ọmọde 5

Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀

àtúnṣe

Ìpínlẹ̀ Rivers ni Ihua ti wá, ó sì lọ sí ilé-ìwé girama ti Mariam Girls.[1]

Iṣẹ́ tó yàn láàyò

àtúnṣe

Ó ti ṣe ìfihàn nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ fíìmù ilẹ̀ Nàìjíríà, tí iye rẹ̀ á máa lọ ọgọ́rùn-ún (100).[2]

Àtòjọ àwọn fíìmù rẹ̀

àtúnṣe
  • Domitila
  • The Millions
  • Unpredictable
  • Unplanned
  • The Game
  • Mama's big stick[3]
  • Spirit of love
  • Masked[4]
  • Legend at 60[5]

Ìgbésí ayé ara ẹni

àtúnṣe

Ihua ti ṣe ìgbéyàwó, ó sì bí ọmọ márùn-ún.[6]

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Maureen Ihua: I Stopped Acting to Take Care of My Handsome Husband". www.thisdaylive.com. Archived from the original on 2022-08-02. Retrieved 2022-08-02. 
  2. "Maureen Ihua: I Stopped Acting to Take Care of My Handsome Husband". www.thisdaylive.com. Archived from the original on 2022-08-02. Retrieved 2022-08-02. 
  3. iliya, rejoice (2022-04-08). "Six Binge-Worthy Movies To Entertain You This Weekend". Daily Trust (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-08-02. 
  4. "My movies demonstrate societal issues people shy away from – Sunny Okonkwo". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-07-14. Retrieved 2022-08-02. 
  5. Augoye, Jayne (2018-01-08). "Davido stars in new Nollywood film". Premium Times Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-08-02. 
  6. "Maureen Ihua: I Stopped Acting to Take Care of My Handsome Husband". www.thisdaylive.com. Archived from the original on 2022-08-02. Retrieved 2022-08-02.