Michael Sata
Michael Chilufya Sata (6 July 1937 – 28 October 2014) je oloselu ara ile Zambia to je Aare ile Zambia ikarun, lati 23 September 2011 titi to fi ku ni 28 October 2014. Oloselu awujo ni,[2] o lewaju egbe oselu Patriotic Front (PF), ni Zambia. Labe Aare Frederick Chiluba, Sata je alakoso eto ni ewadun 1990 gegebi ikan lara awon to se ijoba Movement for Multiparty Democracy (MMD).
Michael Sata | |
---|---|
5th President of Zambia | |
In office 23 September 2011 – 28 October 2014 | |
Vice President | Guy Scott |
Asíwájú | Rupiah Banda |
Arọ́pò | Guy Scott (Acting) |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Mpika, Northern Rhodesia | 6 Oṣù Keje 1937
Aláìsí | 28 October 2014 King Edward VII's Hospital, London, United Kingdom | (ọmọ ọdún 77)
Resting place | Embassy Park, Lusaka 15°25′19″S 28°18′34″E / 15.421884°S 28.309314°E |
Ọmọorílẹ̀-èdè | Zambian |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Patriotic Front (2001–2014) MMD (1991–2001) UNIP (Before 1991) |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Margaret Manda (?-?) Christine Kaseba (?-2014; his death) |
Àwọn ọmọ | 8[1] |
Occupation | Police officer and trade unionist |
Nickname(s) | King Cobra |
Website | Michael Sata lórí Facebook |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokas
àtúnṣe- ↑ Bariyo, Nicholas (29 October 2014). "Zambia President Michael Sata Dies". WSJ. Retrieved 29 October 2014.
- ↑ "We are social democrats". Archived from the original on 2023-05-18. Retrieved 2017-10-28.