Microlophus albemarlensis
Alángba àpáta Galápagos (Microlophus albemarlensis), tí wọ́n tún mọ̀ sí Alángba àpáta Albemarle, jẹ́ ẹ̀yà alángba àpáta tí ó wọ́pọ̀ ní erékùṣù Galápagos níbi tí ó ti wà ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ erékùṣù ìwọ̀ oòrùn archipelago: àwọn erékùṣù ńlá, Isabela, Santa Cruz, Fernandina, Santiago àti Santa Fe, àti àwọn ọ̀pọ̀lọpọ erékùṣù kékèké: Seymour, Baltra, Plaza Sur, Daphne Major àti Rábida.[1] Ó jẹ́ erékùṣù tí ó tàn káàkiri jùlọ nínú gbogbo èyà Galápagos ti Microlophus, a máa ń rí àwọn tókù lẹ́ẹ̀kànkan ní àwọn erékùṣù.[2] Àwọn olùkọ̀wé míràn rò wípé ọ̀pọ̀lọpọ̀ tí wọ́n maa ń rí ní Santiago, Santa Cruz, àti Santa Fe (tí ó wà pẹ̀pú àwọn erékùṣù kékèké) yàtọ sí àwọn ẹ̀yà (M. jacobi, M. indefatigabilis àti M. barringtonensis).[3] Wọ́n máa ń kó àwọn ẹ̀yà wọ̀nyí mọ́ ìdílé Microlophus ṣùgbọ́n ní ìgbà láéláè, wọ́n kó wọn pọ̀ pẹ̀lú Tropidurus.
Microlophus albemarlensis | |
---|---|
Abo ní erékùṣù Santa Fe | |
Akọ ní erékùṣù Isabela | |
Ipò ìdasí | |
Not evaluated (IUCN 3.1)
| |
Ìṣètò onísáyẹ́nsì | |
Ìjọba: | |
Ará: | |
Ẹgbẹ́: | |
Ìtò: | |
Suborder: | |
Ìdílé: | |
Ìbátan: | |
Irú: | M. albemarlensis
|
Ìfúnlórúkọ méjì | |
Microlophus albemarlensis (Baur, 1890)
| |
Pupa ẹ̀ ní àwọn eŕkùṣù Galápagos | |
Synonyms[1] | |
|
Àpèjúwe
àtúnṣeÀgba Galápagos lava lizards ma ń gùn tó bíi 50 to 100 mm SVL (ẹnu -dé-ìdí; láì sí ìdí ẹ̀ níbẹ̀ tàbí gùn ju bẹ́ẹ̀ sí SVL) , ìtóbi sí wọn sì yàtọ káàkiri erékùṣù. Àwọn akọ ma ń tóbi ju abo lọ, tí wọ́n sì ma ń wúwo tóbi tó méjì ọ̀kọ̀ọ̀kan abo, ó sì ma ń tobí tó ìwọn 77 sí 91 mm SVL, àkàwé 63–71 mm ti obìnrin.[4]
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ 1.0 1.1 Microlophus albemarlensis, The Reptile Database
- ↑ Andy Swash; Rob Still; Ian Lewington (2005). Birds, Mammals, and Reptiles of the Galápagos Islands: An Identification Guide. Yale University Press. pp. 120–121. ISBN 978-0-300-11532-1. http://books.google.com/books?id=9s3p8TfXAq8C&pg=PA120.
- ↑ Stebbins, Robert C.; Lowenstein, Jerold M.; Cohen, Nathan W. (1967). "A Field Study of the Lava Lizard (Tropidurus albemarlensis) in the Galapagos Islands". Ecology 48 (5): 839–851.. doi:10.2307/1933742. JSTOR 1933742.