Microlophus delanonis, alángbà àpáta Española  tàbí alángbà àpáta Hood wọ́pọ̀ ní erékùṣù Galapagos ti  Española. [1]Wọ́n maa ń kó àwọn ẹ̀yà wọ̀nyí pọ̀ sí ìdílé Microlophus ṣùgbọ́n wọ́n ti kà wọn sí ìdílé Tropidurus tẹ́lẹ̀.[2]

Alángbá àpáta Espańola
Akọ
Abo
Ìṣètò onísáyẹ́nsì
Ìjọba:
Ará:
Ẹgbẹ́:
Ìtò:
Suborder:
Ìdílé:
Ìbátan:
Irú:
M. delanonis
Ìfúnlórúkọ méjì
Microlophus delanonis
(Baur, 1890)
Synonyms
  • Tropidurus delanonis
  • Tropidurus hoodensis

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Benavides,E; Baum, R.; Snell, H. M.; Snell, H. L.; and Sites, Jr., J. W. (2009) "Island Biogeography of Galápagos Lava Lizards (Tropiduridae: Microlophus): Species Diversity and Colonization of the Archipelago." Archived 2013-09-21 at the Wayback Machine. (.pdf) Evolution, 63 (6): 1606–1626.
  2. Microlophus bivittatus, Reptile Database