Microlophus peruvianus
Microlophus peruvianus, ti Peru Pacific iguana, jẹ́ àwọn ẹ̀yà alángba àpáta tí ó wọ́pọ̀ ní Ecuador, Peru, àti Chile. Wọ́n maa ń kó àwọn ẹ̀yà wọ̀nyí pọ̀ sí ìdílé Microlophus ṣùgbọ́n wọ́n ti kà wọn sí ìdílé Tropidurus tẹ́lẹ̀[1]
Peru Pacific iguana | |
---|---|
Ìṣètò onísáyẹ́nsì | |
Ìjọba: | |
Ará: | |
Ẹgbẹ́: | |
Ìtò: | |
Suborder: | |
Ìdílé: | |
Ìbátan: | |
Irú: | M. peruvianus
|
Ìfúnlórúkọ méjì | |
Microlophus peruvianus (Lesson, 1830)
| |
Subspecies | |
| |
Synonyms | |
|
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Microlophus peruvianus, Reptile Database
Àyọkà alángbá yí jẹ́ kúkurú. Olè ran Wikipedia lọ́wọ́ lati fẹ̀ẹ́ síi. |