Mohammed Ali Ndume

Olóṣèlú Nàìjíríà

Mohammed Ali Ndume jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí wọ́n dìbò yàn wọlé gẹ́gẹ́ bí aṣojú ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin kékeré ti ilẹ̀ Nàìjíríà lati ọdún 2003 sí 2011. Wọ́n dìbò yàn wọlé gẹ́gẹ́ bí aṣojú Gúúsù Borno State ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà. Ó jẹ́ aṣojú ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin lẹ́yìn tí ó wọlé látàrí ètò ìdìbò ti oṣù kẹrin ọdún 2011 lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú People's Democratic Party, PDP.[1][2] [3]

Mohammed Ali Ndume
Mohammed Ali Ndume
Aṣojú Chibok ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin kékeré ti ilẹ̀ Nàìjíríà
In office
Ọdún 2003 – 2011
Aṣojú Gúúsù Borno State ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
Oṣù karú Ọdún 2011
AsíwájúOmar Hambagda
Àwọn àlàyé onítòhún
Ẹgbẹ́ olóṣèlú People's Democratic Party

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. DAUDA MBAYA (31 December 2010). "Ndume Picks PDP Membership Card, Tackles ANPP". Leadership. Archived from the original on 2011-07-22. Retrieved 2011-05-04. 
  2. Mustapha Isah Kwaru (9 January 2011). "Ndume’s defection and the fate of ANPP in Southern Borno". Peoples Daily. Retrieved 2011-05-04. 
  3. "Collated Senate results". INEC. Archived from the original on 2011-04-19. Retrieved 2011-05-04.