Omar Hambagda

Olóṣèlú Nàìjíríà

Omar Hambagda jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí wọ́n dìbò yàn wọlé gẹ́gẹ́ bí aṣojú ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà lati ọdún 2003 sí 2011. Wọ́n dìbò yàn wọlé gẹ́gẹ́ bí aṣojú Gúúsù Borno ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà lábẹ́ òṣèlú All Nigeria Peoples Party (ANPP) ní ọdún 2003.[1] Wọ́n tun yàn ní ọdún 2007, tí ó sì di ipò yìí mú di ọdún 2011 lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú People's Democratic Party, PDP.[2][3][4]

Omar Abubakar Hambagda
Aṣojú Gúúsù Borno ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà
In office
Oṣù karún ọdún 2003 – Oṣù karún ọdún 2011
AsíwájúAbubakar Mahdi
Arọ́pòMohammed Ali Ndume
ConstituencyGúúsù Borno
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí28 Oṣù Keje 1949 (1949-07-28) (ọmọ ọdún 75)
AláìsíOṣù karún ọdún 2016
Ẹgbẹ́ olóṣèlúAll Nigeria Peoples Party (ANPP)
ProfessionOnímọ̀ ẹ̀kọ́ àti olóṣèlú

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. ISMAIL OMIPIDAN (February 10, 2008). "Northern Senators’ Forum coup: How Shagaya was toppled". Daily Sun. Retrieved 2009-10-05. 
  2. Emmanuel Aziken (27 January 2008). "Fraudstars in National Assembly - Two Panel Chairmen in Aliyu's List". Vanguard. Retrieved 2009-10-05. 
  3. "Nigeria Senate probe report on Ghana visit under the carpet?". Ghana Business. Sep 22, 2009. Archived from the original on 2011-08-15. Retrieved 2009-10-05. 
  4. TUNJI OLAWUNI & KEHINDE AKINTOLA (25 May 2009). "How sleaze, scandals rock National Assembly". Business Day. Archived from the original on 2011-07-08. Retrieved 2009-10-05.