Moji Solar-Wilson tí wọ́n bí ní ọdún 1968, ni ó jẹ́ ọmọ bíbí ìlú ìjerò ÈkìtìÌpínlẹ̀ Èkìtì. [1])[2] jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè a Nàìjíríà, àmọ́ tí ó fi ilú Wngland ṣe ibùgbé jẹ́ alàgàta láàrín (Broker) òntà àti ònrà, ó ń bani ralé ralẹ̀, bẹ́ẹ̀ ni ó jẹ́ ọ̀kan lára awọn LGBTQIA+, a jà fẹ́tọ́ ọmọnìyàn, aláríwísí àwùjọ àti olùdásílẹ̀ Solar Worlwide Inú.

Moji Solar-Wilson
Ọjọ́ìbíMoji Solar Percy
Orílẹ̀-èdèNàìjíríà
Iṣẹ́Activist, coach, social commentator

Ní ọdún 2017, ó ṣe ìgbéyàwó pẹ̀lú oobìnrin ẹgbẹ́ rẹ̀ Margaret Wilson,[3] ó sì di obìnrin akọ́kọ́ tí ó jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí yóò dán irú rẹ̀ wò.[4]

Àwọn ìtọ́ka sí àtúnṣe

  1. "53-yr-old Nigerian woman marries lesbian partner in the US". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2017-04-24. Retrieved 2021-06-16. 
  2. "Nigerian lesbian lady, Moji Solar-Wilson, shares new photo with her wife". Gistmattaz. Archived from the original on 2021-06-28. Retrieved 2021-06-16. 
  3. "Nigerian Lesbian, Moji Solar-Wilson, Shares New Photo With Her Wife – My Celebrity & I" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2021-06-24. Retrieved 2021-06-16. 
  4. "An Authentic Experience". OutSmart Magazine (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-05-03. Retrieved 2021-06-16. 

Àdàkọ:Authority control