Monica Friday
Monica Friday (tí a bí ní ọjọ́ ọ̀kàn-dín-lógún oṣù kẹrin, ọdún 1988) jẹ́ Òṣèré Fíìmù Ilẹ̀ Nàìjíríà, oní-ipa, realtor, model àti olùdarí ètò.[1][2][3]
Monica Friday | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Monica Friday 19 Oṣù Kẹrin 1988 Badagry, Lagos, Nigeria |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Iṣẹ́ | Actress, influencer, realtor, model and producer |
Ìgbà iṣẹ́ | 2008–present |
Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ Ayé Àti Ẹ̀kọ́ Rẹ̀
àtúnṣeA bí Monica ní Badagry ó sì dàgbà ní Ajégúnlẹ̀, àdúgbò tí ó wà ní ìlú Èkó sínú ilé Onígbàgbọ́. Ó bẹ̀rẹ̀ Ẹ̀kọ rẹ̀ ní Ilé-ẹ̀kọ́ Mistermis Kiddies. Ó parí ilé-ìwé gírámà ní ilé-ìwé gíga (Newland Senior Secondary), Èkó kó tó di pé ó lọ sí Yunifásítì Olabisi Onabanjo, ní ìpínlẹ̀ Ògùn níbi tó ti kàwé 'Mass Communication'. [4]
Iṣẹ́ Rẹ̀
àtúnṣeÓ ṣe ìfarahàn tẹlifísàn àkọ́kọ́ rẹ̀ tí ó ṣe ipa bí àfikún nínú iṣẹ́ àkànṣe Wale Adenuga tí àkọ́lé rẹ̀ ni 'New Song', Ipa fíìmù àkọ́kọ́ gbòógì rẹ̀ jẹ́ ní ọdún 2015 nígbà tí ó farahàn ní fíìmù Remi Vaughan-Richards 'Unspoken'.[5]
Monica ti ṣe ìfarahàn ní járá M-Net tí ó gùn-gùn ọdún 2015, “Do Good” àti Fíìmù Tale Africa “Dérè” tí a tú sílẹ̀ ní ọdún 2016. [6][7] Ní ọdún 2019, Ó farahàn nínú fíìmù “Zena” bí Rexiha. [8][9]
Járá Tẹlifísàn Rẹ̀
àtúnṣe- Do Good [10]
- The Village Headmaster
- Dérè
- Flat Mates
- So Wrong, So Good
Àwọn Fíìmù Rẹ̀
àtúnṣe- Bad Generation (2008)
- Being Mrs Elliot (2014)
- The King's Cross (2019)
- October 1 (2014)
- Murder at Prime Suites (2013)
- The First Lady (2015)
- Wives on Strike (2014)
- Abducted (2015)
- Zena (2019) [11]
- Mothers & Daughters In-Law (2019) [12]
- Timeless Passion (2020)
- Unspoken (2015)
- Labour Room (2017) [13]
- Iquo's Journal (2015)
- Cliché (2016)
- Hoodrush (2012)
- Two Brides And A Baby (2011) [14]
- Bonny & Clara (2019) [15]
- Savior(2015) [16]
- My Body My Proud (2020) [17]
- Silent Murder (2021) [18]
Àwọn Ìṣẹ̀dá
àtúnṣeÀwọn Ìtọ́ka Sí
àtúnṣe- ↑ "Actress, Monica Friday Speaks On Sleeping With Movie Producers To Get Famous". lifestyle.ng. 22 November 2020. Archived from the original on 10 May 2021. Retrieved 18 June 2021.
- ↑ "I once hawked Ewa Agoyin in Ajegunle – Monica Friday". dailytimes.ng. Retrieved 17 June 2021.
- ↑ "Watch Femi Branch, Monica Friday in short film". pulse.ng. 29 December 2015. Retrieved 17 June 2021.
- ↑ "monica friday". mybiohub.com. 26 September 2016. Retrieved 17 June 2021.
- ↑ "Unspoken". filmfreeway.com. Retrieved 17 June 2021.
- ↑ "Most difficult part of being famous is being broke – Monica Friday". punchng.com. 23 June 2019. Retrieved 17 June 2021.
- ↑ "Dérè: An African Tale – TV Show : Cast, Details, Plot, Release, Runtime, Rating, Downloads". otakuwire.com. Retrieved 18 June 2021.
- ↑ "Watch Official Trailer for 'ZENA' starring Ireti Doyle, Omowunmi Dada & Ijeoma Grace Agu". bellanaija.com. 20 April 2019. Retrieved 18 June 2021.
- ↑ "ZENA". nollywoodreinvented.com. 6 January 2020. Retrieved 18 June 2021.
- ↑ "New African Magic Comedy Series Premiere – do Good". 8 July 2015. Archived from the original on 12 October 2020. Retrieved 23 April 2023.
- ↑ "Zena (2019) - IMDb". IMDb.
- ↑ "NOLLYWOOD MOVIES: 'Mothers & Daughters in-law' Starring Ebele Okaro, Iyabo Ojo, Kenneth Okolie, Monica Friday, Rachel Oniga, Shaffy Bello in Cinemas next week- See trailer!". Archived from the original on 2021-10-07. Retrieved 2023-04-23.
- ↑ "Labour Room (2017) | Casts and Crew | INSIDENOLLY". Archived from the original on 2021-06-24. Retrieved 2023-04-23.
- ↑ "Two Brides and a Baby (2011) | Casts and Crew | INSIDENOLLY". Archived from the original on 2021-10-06. Retrieved 2023-04-23.
- ↑ "COMING SOON: Bonny & Clara". 12 September 2019.
- ↑ "New Movie Alert: Best Okoduwa's Short Film 'SAVIOR'".
- ↑ "My Body, My Pride: Actress Wini dedicates film to Tinubu, Bello". 27 February 2021.
- ↑ "Movie Review: Lack of Depth Undoes 'Silent Murder'". 31 May 2021. Archived from the original on 23 April 2023. Retrieved 23 April 2023.
- ↑ "Yoruba Demons (TBD) - nlist | Nollywood, Nigerian Movies & Casting".
- ↑ "Showmax".